Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

Ìsọfúnni Nípa Ọ́fíìsì àti Rírìn Yí Ká Ọgbà

Tayọ̀tayọ̀ la pè ẹ́ kó o wá rìn yí ká ọ́fíìsì wa àtàwọn ibi tá a ti ń tẹ̀wé. Wá ọ́fíìsì wa tó o lè lọ àti àsìkò tó o lè rìn yí ọgbà wa ká.

Brazil

Rodovia SP-141 - km 43

CESÁRIO LANGE-SP

18285-901

BRAZIL

+55 15-3322-9000

Wíwo Ọgbà Wa Yíká

Monday sí Friday

8:00 àárọ̀ sí 9:45 àárọ̀ àti 1:00 ọ̀sán sí 2:45 ọ̀sán

Ó máa gba nǹkan bíi wákàtí méjì

Àwọn iṣẹ́ tí à ń ṣe níbẹ̀

À ń tẹ àìmọye mílíọ̀nù ìwé, ìwé pẹlẹbẹ, ìwé ìròyìn àti àṣàrò kúkurú ní èdè tó lé ní ọgọ́fà [120] lọ́dọọdún.

Àwọn Àtẹ Tó O Lè Wò Fúnra Ẹ

Àtẹ tá a pè ní The Bible—The Book and Its Author. Àtẹ yìí máa jẹ́ kó o rí bí Bíbélì ṣe tẹ̀ wá lọ́wọ́ lónìí àti bí Òǹṣèwé Bíbélì ṣe pa ọ̀rọ̀ tó wà nínú rẹ̀ látìbẹ̀rẹ̀ mọ́ láìka bí àwọn alátakò ṣe gbìyànjú láti yí ọ̀rọ̀ inú rẹ̀ pa dà.

Wa ìwé pẹlẹbẹ tó ń ṣàlàyé ẹ̀ka ọ́fíìsì wa jáde.