Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

Ìsọfúnni Nípa Ọ́fíìsì àti Rírìn Yí Ká Ọgbà

Tayọ̀tayọ̀ la pè ẹ́ kó o wá rìn yí ká ọ́fíìsì wa àtàwọn ibi tá a ti ń tẹ̀wé. Wá ọ́fíìsì wa tó o lè lọ àti àsìkò tó o lè rìn yí ọgbà wa ká.

Benin

ARTJB (Association religieuse des Témoins de Jéhovah du Bénin)

Route Inter-Etat Cotonou-Parakou

AB-CALAVI

BENIN

+229 97-97-00-60

+229 21-36-01-14

Wíwo Ọgbà Wa Yíká

Monday sí Friday

8:00 àárọ̀ sí 10:45 àárọ̀ àti 1:00 ọ̀sán sí 3:45 ọ̀sán

Ó máa gba ìṣẹ́jú 45

Àwọn iṣẹ́ tí à ń ṣe níbẹ̀

À ń túmọ̀ àwọn ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì sí èdè Bariba, Fon, Gun, Jula, Kabiye, Moore àti Zarma. À ń kó àwọn ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ ránṣẹ́ sí àwọn ìjọ àti àwùjọ tó lé ní ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta [500] lórílẹ̀-èdè Benin, Burkina Faso, Niger àti Togo.

Wa ìwé pẹlẹbẹ tó ń ṣàlàyé ẹ̀ka ọ́fíìsì wa jáde.