Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìsọfúnni Nípa Ọ́fíìsì àti Rírìn Yí Ká Ọgbà

Tayọ̀tayọ̀ la pè ẹ́ kó o wá rìn yí ká ọ́fíìsì wa àtàwọn ibi tá a ti ń tẹ̀wé. Wá ọ́fíìsì wa tó o lè lọ àti àsìkò tó o lè rìn yí ọgbà wa ká.

Argentina

Av. Elcano 3820 PB Chacarita

C1427BVV CDAD. AUT. DE BUENOS AIRES

ARGENTINA

+54 11-3220-5900

GPS Coordinates: -34.581015, -58.460560

Wíwo Ọgbà Wa Yíká

Monday sí Friday

8:30 àárọ̀ sí 10:30 àárọ̀ àti 1:30 ọ̀sán sí 3:30 ọ̀sán. Wákàtí-wákàtí la máa ń mú àwọn àlejò rìn yíká ọgbà.

Ó máa gba wákàtí kan ààbọ̀

Àwọn iṣẹ́ tí à ń ṣe níbẹ̀

À ń bójú tó ìṣẹ́ àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà tó wà ní orílẹ̀-èdè Argentina àti Uruguay. À ń túmọ̀ àwọn ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì sí Èdè Àwọn Adití Lọ́nà ti Argentina, Èdè Àwọn Adití Lọ́nà ti Uruguay, èdè Romany (Argentina) àtàwọn èdè ìbílẹ̀ mẹ́rin, ìyẹn Pilagá, Quichua (Santiago del Estero), Toba àti Wichi.

Wa ìwé pẹlẹbẹ tó ń ṣàlàyé nípa ẹ̀ka ọ́fíìsì wa jáde.