Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

Ìsọfúnni Nípa Ọ́fíìsì àti Rírìn Yí Ká Ọgbà

Tayọ̀tayọ̀ la pè ẹ́ kó o wá rìn yí ká ọ́fíìsì wa àtàwọn ibi tá a ti ń tẹ̀wé. Wá ọ́fíìsì wa tó o lè lọ àti àsìkò tó o lè rìn yí ọgbà wa ká.

Àméníà

38 Keri Street

0028 YEREVAN

ARMENIA

+374 10 708 200

Wíwo Ọgbà Wa Yí Ká

Monday sí Friday

9:30 àárọ̀ sí 11:⁠00 àárọ̀ àti 2:00 ọ̀sán sí 4:00 ìrọ̀lẹ́

Ó máa gba wákàtí kan

Jọ̀ọ́, pè kó o tó wá ká lè sọ ọjọ́ àti àkókò tá a máa lè mú ẹ yí ká ọgbà wa.

Àwọn iṣẹ́ tí à ń ṣe níbẹ̀

À ń túmọ̀ ìwé tó dá lórí Bíbélì sí èdè Àméníà, èdè Àméníà táwọn afọ́jú ń lò, Èdè Àwọn Adití Lọ́nà ti Àméníà àti èdè Karabakh. À ń bójú tó iṣẹ́ àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà tí iye wọn jẹ́ 10,974 ní Àméníà. Wàá rí ìpàtẹ kan tó o bá wá.

Wa Ìwé Tó Ń Ṣàlàyé Ẹ̀ka Ọ́fí ìsì Wa Jáde