Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

ÀWỌN IṢẸ́ ÌKỌ́LÉ

Fọ́tò Oríléeṣẹ́ Wa Tuntun ní Warwick, Apá 7 (September 2016 sí February 2017)

Gbogbo ilé tó wà ní oríléeṣẹ́ wa ní Warwick la ti ń lò báyìí. Ní Àwọn Ọ́fíìsì àti Ilé Tó Wà fún Onírúurú Iṣẹ́, ó lé ní 250 èèyàn tó ṣiṣẹ́ lórí àwọn ìpàtẹ yìí látìbẹ̀rẹ̀ dé ìparí àtàwọn ohun ìṣẹ̀ǹbáyé tó wà nínú rẹ̀.

BÍ NǸKAN ṢE RÍ NÍ BẸ́TẸ́LÌ

A Pè Ẹ́ Kó O Wá Wo Àwọn Ọ́fíìsì Wa Tó Wà ní Bẹ́tẹ́lì Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà

Wàá rí Oríléeṣẹ́ Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà àti ẹ̀ka ọ́fíìsì wa lórílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà.

Ìwé Ọdọọdún Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà​—2017

“Ẹ̀yin Ni Aládùúgbò Tó Dáa Jù Lọ”

Ní May 7 àti 8, ọdún 2016, tó bọ́ sópin ọ̀sẹ̀, a ṣí ọ́fí ìsì wa tó wà ní Brooklyn sílẹ̀ káwọn èèyàn lè wá wo ìpàtẹ tó dá lórí ìtàn Bíbélì, èyí sì mú káwọn aládùúgbò gbọ́ ìwàásù.

Ìwé Ọdọọdún Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà​—2017

Àwọn Ohun Pàtàkì Tó Ṣẹlẹ̀ Lọ́dún Tó Kọjá

Àwọn ìròyìn yìí jẹ́ ká rí i pé àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà kárí ayé ń fi hàn pé a gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà, à ń ṣe rere, a sì ń fi ìṣòtítọ́ báni lò.—Sáàmù 37:3.

ÀWỌN IṢẸ́ ÌKỌ́LÉ

Àwọn Ẹlẹ́rìí Ò Pa Àwọn Ẹran Igbó àti Àyíká Lára Nílùú Warwick

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ti bẹ̀rẹ̀ sí í kọ́ oríléeṣẹ́ wọn tuntun sí ìpínlẹ̀ New York. Kí ni wọ́n ń ṣe kí wọn má bàa pa àyíká lára?

ÀWỌN IṢẸ́ ÌKỌ́LÉ

Bọ́rọ̀ Ṣe Rí Lára Àwọn Tó Ń Bá Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ṣiṣẹ́ ní Warwick

Ìrírí wo làwọn òṣìṣẹ́ kan tí kì í ṣe Ẹlẹ́rìí àtàwọn tó ń wa bọ́ọ̀sì ní nígbà tí wọ́n ń bá àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ṣiṣẹ́ ìkọ́lé?

IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

Àwọn Ọmọ Ìbílẹ̀ Amẹ́ríkà Gbọ́ Tuntun Níbi tí Wọ́n Ti Ń Ṣayẹyẹ Nílùú New York

Àwọn ìwé ìròyìn tó wà láwọn èdè ìbílẹ̀ Amẹ́ríkà táwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà pàtẹ níbi ayẹyẹ ‘Gateway to Nations’ tó wáyé lọ́dún 2015 wú àwọn èèyàn lórí gan-an.

ÀWỌN IṢẸ́ ÌKỌ́LÉ

Ìlú Warwick Gbàlejò

Àwọn aráàlú Warwick ní ìpínlẹ̀ New York sọ̀rọ̀ nípa bó ṣe rí lára wọn láti bá àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ṣiṣẹ́ ní oríléeṣẹ́ wa tuntun tá à ń kọ́.

BÍ NǸKAN ṢE RÍ NÍ BẸ́TẸ́LÌ

Àkànṣe Ìpàtẹ Bíbélì

Láti ìgbà tí Jèhófà Ọlọ́run ti dá èèyàn sáyé ló ti jẹ́ kí wọ́n mọ orúkọ òun. Wo fídíò yìí kó o lè rí bí àwọn ìtúmọ̀ Bíbélì kan ṣe pa orúkọ Ọlọ́run mọ́ láti ọ̀pọ̀ ọdún títí di ìsìnsìnyí.

ILÉ ÌṢỌ́ (Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́)

Wọ́n Yọ̀ǹda Ara Wọn Tinútinú—ní New York

Kí nìdí tí tọkọtaya kan tó rí towó ṣe fi kó kúrò nínú ilé ńlá tí wọ́n nífẹ̀ẹ́ sí gan-an, tí wọ́n sì kó lọ sí yàrá kékeré kan?