Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

ÀWỌN IṢẸ́ ÌKỌ́LÉ

Àwọn Fọ́tò Iṣẹ́ Ìkọ́lé Ẹ̀ka Ọ́fíìsì Wa ní Philippines, Apá 1 (February 2014 sí May 2015)

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ń kọ́ àwọn ilé tuntun sí ẹ̀ka ọ́fíìsì wa tó wà nílùú Quezon ní Philippines, a sì ń tún àwọn èyí tó ti wà níbẹ̀ tẹ́lẹ̀ ṣe.

ILÉ ÌṢỌ́ (Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́)

Wọ́n Yọ̀ǹda Ara Wọn Tinútinú ní Philippines

Kẹ́kọ̀ọ́ nípa ohun tó mú kí àwọn kan fi iṣẹ́ tí wọ́n ń ṣe sílẹ̀, kí wọ́n ta àwọn ohun ìní wọn, tí wọ́n sì lọ sí àdádó ní orílẹ̀-èdè Philippines.