Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá
  • Tokyo, Japan​—Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ń fi ìkànnì jw.org wàásù fún obìnrin adití kan

  • Kamaishi, Japan​—⁠Lẹ́yìn ìmìtìtì ilẹ̀ àti àkúnya omi tó wáyé lọ́dún 2011, àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ń bá àwọn tó yè é sọ̀rọ̀ ní ibi tí wọ́n ń gbé fúngbà díẹ̀

ILÉ ÌṢỌ́ (Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́)

Ebun Pataki Kan To Wa fun Awon Ara Japan

A gbe iwe tuntun kan ta a pe akori re ni,‘The Bible—The Gospel According to Matthew’ jade lede Japan. Awon ohun wo lo wa ninu iwe yii? Ki nidi ti eto Olorun fi se e?