Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá
 • Zagreb, Croatia​—Ẹlẹ́rìí kan ń fún ẹnì kan ní ìwé ìròyìn Ilé Ìṣọ́ ní òpópónà Ilica

 • Rovinj, Croatia​—Wọ́n ń fi ìwé Ìròyìn Ayọ̀ Látọ̀dọ̀ Ọlọ́run! lọni

 • Rovinj, Croatia​—Wọ́n ń fi ìwé Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an? ṣe ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì

 • Zagreb, Croatia​—Wọ́n ń fi ìwé àṣàrò kúkúrú Ibo La Ti Lè Rí Ìdáhùn sí Àwọn Ìbéèrè Pàtàkì Nípa Ìgbésí Ayé? lọni

 • Zagreb, Croatia​—Wọ́n ń sọ̀rọ̀ ìrètí tó wà nínú Bíbélì

 • Pula, Croatia​—Wọ́n ń fi àṣàrò kúkúrú, Kí Ló Máa Ṣẹlẹ̀ Lọ́jọ́ Ọ̀la? lọni nítòsí gbọ̀ngàn ìwòran àwọn ará Róòmù àtijọ́

 • Rovinj, Croatia​—Wọ́n ń wàásù nípa Ìjọba Ọlọ́run

Ìsọfúnni Ṣókí—Croatia

 • 4,240,000—Iye àwọn èèyàn
 • 5,335—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
 • 64—Iye àwọn ìjọ
 • 795—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún