Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá
  • London, England​—⁠Wọ́n ń bá àwọn tó ń sọdá afárá Westminster Bridge sọ̀rọ̀

ÀWỌN IṢẸ́ ÌKỌ́LÉ

Àwọn Fọ́tò Iṣẹ́ Ìkọ́lé Ẹ̀ka Ọ́fíìsì Wa ní Ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì, Apá 2 (September 2015 sí August 2016)

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà tó yọ̀ǹda ara wọn àtàwọn agbaṣẹ́ṣe ti ń ṣètò ilẹ̀ tí wọ́n máa kọ́ ẹ̀ka ọ́fíìsì náà sí àti ibi tí wọ́n máa kọ́lé tí wọ́n á máa kó irinṣẹ́ sí, táwọn òṣìṣẹ́ á sì máa gbé kí wọ́n tó ṣiṣẹ́ ìkọ́lé ńlá yìí tán.

ÀWỌN IṢẸ́ ÌKỌ́LÉ

Wọn Ò Pa Ẹran Igbó Lára Nílùú Chelmsford

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà tó wà ní Ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì ti bẹ̀rẹ̀ sí í kọ́ ẹ̀ka ọ́fíìsì wọn tuntun sí tòsí ìlú Chelmsford. Kí ni wọ́n ń ṣe kí wọ́n má bàa pa ẹran igbó lára?