Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá
  • Rostock, Germany​—Wọ́n ń sọ̀rọ̀ ìtùnú látinú Bíbélì nígbà tí wọ́n ń wàásù ní etíkun

  • Marburg, Germany​—Wọ́n ń sọ̀rọ̀ ìrètí látinú Bíbélì ní tòsí àgọ́ àwọn tí ogun lé wá láti orílẹ̀-èdè míì

  • Rostock, Germany​—Wọ́n ń sọ̀rọ̀ ìtùnú látinú Bíbélì nígbà tí wọ́n ń wàásù ní etíkun

  • Marburg, Germany​—Wọ́n ń sọ̀rọ̀ ìrètí látinú Bíbélì ní tòsí àgọ́ àwọn tí ogun lé wá láti orílẹ̀-èdè míì

IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

Wọ́n Wàásù fún Àwọn Sinti àti Àwọn Roma Lórílẹ̀-èdè Jámánì

Nígbà àkànṣe ìwàásù táwọn Ẹlẹ́rìí ṣe lọ́dún 2016, wọ́n pín àṣàrò kúkúrú tó fẹ́rẹ̀ẹ́ tó 3,000, wọ́n bá àwọn Sinti àti Roma tó lé ní 360 sọ̀rọ̀, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í kọ́ àwọn 19 lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì.

IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

Wọ́n Rìn Gba Àárín Òkun Kọjá Láti Lọ Wàásù

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ní ọ̀nà kan tó ṣàrà ọ̀tọ̀ tá a fi lè lọ wàásù fún àwọn tó ń gbé ní erékùṣù kan tí wọ́n ń pè ní Halligen.