Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo ohun yíyàn míì

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yorùbá

A Fẹ́ Kí O Wá sí Àpéjọ Wa

A Fẹ́ Kí O Wá sí Àpéjọ Wa

Ọ̀pọ̀ èèyàn máa ń ní ìjákulẹ̀, àmọ́ Bíbélì sọ pé ká ‘Má Sọ̀rètí Nù!’ Àpéjọ àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ti ọdún yìí máa jẹ́ ká mọ ohun tá a lè ṣe ká lè láyọ̀ báyìí, káyé wa sì dùn bí oyin lọ́jọ́ iwájú.