Àwọn èèyàn láti ọ̀pọ̀ orílẹ̀-èdè, tí èdè àti ẹ̀yà wọn yàtọ̀ síra máa ń gbádùn àwọn ẹ̀kọ́ Bíbélì àti ìbákẹ́gbẹ́ Kristẹni láwọn àpéjọ àgbáyé wa fáwọn ọjọ́ mélòó kan.