Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Yan èdè Yorùbá

Àwọn Àpéjọ tí Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Máa Ń Ṣe Lọ́dọọdún

Ọdọọdún làwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà máa ń kóra jọ láti ṣe àpéjọ ọlọ́jọ́ mẹ́ta. A máa ń gbọ́ àwọn àsọyé níbẹ̀, a sì máa ń wo àwọn fídíò tó kọ́ wa lóhun tí Bíbélì sọ. Àwọn ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò àtàwọn àṣefihàn tá a tún máa ń ṣe níbẹ̀ máa ń jẹ́ ká mọ bá a ṣe lè máa fi àwọn ìlànà Bíbélì sílò nígbèésí ayé wa. Tayọ̀tayọ̀ la pè ọ́ pé kó o wá. A kì í gbégbá ọrẹ.

 

Wá Ibi Tó Sún Mọ́ Ẹ