Yorùbá
Ọ́fíìsì Wa àti Wíwo Ọgbà: Serbia
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/1011232/univ/art/1011232_univ_sqr_xl.jpg

Ìbẹ̀wò sí Bẹ́tẹ́lì

A rọ̀ ẹ́ pé kó o wá ṣèbẹ̀wò sí àwọn ẹ̀ka ọ́fíìsì wa. Bẹ́tẹ́lì la sábà máa ń pe àwọn ibí yìí. Àwọn kan lára àwọn ọ́fíìsì yìí ní àwọn àtẹ téèyàn lè wò fúnra ẹ̀.

Serbia

Tos̆in bunar 58-60

11080 Beograd (Zemun)

Serbia

+381 11-405-99-00

Wíwo Ọgbà Wa Yíká

Monday sí Friday

8:00 àárọ̀ sí 11:00 àárọ̀ àti 1:00 ọ̀sán sí 4:00 ìrọ̀lẹ́

Ó máa gba wákàtí kan

Àwọn iṣẹ́ tí à ń ṣe níbẹ̀

À ń bójú tó àwọn 3,850 Ẹlẹ́rìí Jèhófà tó wà lórílẹ̀-èdè Serbia àtàwọn 448 tó wà ní Montenegro. À ń ṣètò àpéjọ agbègbè àti àpéjọ àyíká lédè Hungarian, Montenegrin, Romany, Serbian àti Èdè Adití ti Serbia, bákan náà, à ń ṣètò àwọn ilé ẹ̀kọ́ tó dá lórí Bíbélì fún àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà. À ń túmọ̀ ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì sí èdè Montenegrin, Romanian (Vlach), Romany (Serbia), Serbian (lọ́nà ti Cyrillic àti Roman), pẹ̀lú Èdè Adití ti Serbia. À ń gba ohùn sílẹ̀, a sì ń ṣe fídíò láwọn èdè yìí. Bákan náà, à ń ṣe àwọn ìtẹ̀jáde wa lédè àwọn afọ́jú Serbian braille.

Wa ìwé pẹlẹbẹ tó ń ṣàlàyé ẹ̀ka ọ́fíìsì wa jáde.