Yorùbá
Ọ́fíìsì àti Rírìn Yíká Ọgbà: Orílẹ̀-èdè Hungary
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/1011232/univ/art/1011232_univ_sqr_xl.jpg

Ìbẹ̀wò sí Bẹ́tẹ́lì

A rọ̀ ẹ́ pé kó o wá ṣèbẹ̀wò sí àwọn ẹ̀ka ọ́fíìsì wa. Bẹ́tẹ́lì la sábà máa ń pe àwọn ibí yìí. Àwọn kan lára àwọn ọ́fíìsì yìí ní àwọn àtẹ téèyàn lè wò fúnra ẹ̀.

Hungary

BUDAPEST

Kövirózsa u. 1.

H-1163

HUNGARY

+361 401-1100

Wíwo Ọgbà Wa Yíká

Monday sí Friday

10:00 àárọ̀ àti 3:00 ọ̀sán

Ó máa gba wákàtí kan àti ìṣẹ́jú 15

Àwọn iṣẹ́ tí à ń ṣe níbẹ̀

À ń bójú tó ìṣẹ́ àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ní ìjọ 278 tó wà ní orílẹ̀-èdè Hungary, a sì ń ṣètìlẹ́yìn fún àwọn ìjọ tó ń sọ èdè Hungarian ní orílẹ̀-èdè Slovakia àti Ukraine. À ń tú àwọn ìwé tó dá lórí Bíbélì sí èdè Hungarian àti Lovári. A tún máa ń gba ohùn sílẹ̀ fún àwọn ìtẹ̀jáde lédè Hungarian, a sì máa ń ṣe fídíò Èdè Àwọn Adití Lọ́nà ti Hungarian.

Wa ìwé pẹlẹbẹ tó ń ṣàlàyé nípa ẹ̀ka ọ́fíìsì wa jáde.