Wá Àyè fún Jèhófà
Wà á jáde:
1. Lójoojúmọ́
Ọ̀pọ̀ nǹkan wà tá a fẹ́ ṣe.
Síbẹ̀, àdúrà ṣe pàtàkì gan-an!
Àti àwọn nǹkan pàtàkì míì.
(ÈGBÈ)
Wáyè fún Jèhófà,
Kó o lè túbọ̀ sún mọ́ ọn.
Má jẹ́ káwọn nǹkan míì gbàkókò rẹ.
Wáyè fún Jèhófà.
2. Ó yẹ káwọn
Ọ̀rẹ́ jọ máa sọ̀rọ̀.
Táwa náà bá fẹ́ dọ̀rẹ́ Jèhófà,
Ó yẹ ká jọ máa sọ̀rọ̀
Látọkàn.
(ÈGBÈ)
Wáyè fún Jèhófà,
Kó o lè túbọ̀ sún mọ́ ọn.
Má jẹ́ káwọn nǹkan míì gbàkókò rẹ.
Wáyè fún Jèhófà.
(ÀSOPỌ̀)
Wáyè
Láti máa ka Bíbélì
Kó o sì
Ronú lórí ohun tó o kà.
Wàá rí i pé o máa láyọ̀.
Wáyè;
Wáyè;
Jọ̀ọ́ wáyè.
(ÈGBÈ)
Wáyè fún Jèhófà,
Kó o lè túbọ̀ sún mọ́ ọn.
Má jẹ́ káwọn nǹkan míì gbàkókò rẹ.
Wáyè fún Jèhófà.
Wáyè;
Jọ̀ọ́, wáyè.
Wáyè;
Wáyè.
Jọ́ọ̀ wáyè;
Wáyè.
Jọ̀ọ́, wáyè;
Wáyè.

