Ìtàn Ìgbésí Ayé Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà

Kárí ayé, àwọn ará lọ́kùnrin àti lóbìnrin ti fi ìjọsìn Jèhófà ṣáájú láyé wọn. Ìtàn wọn máa fún ẹ níṣìírí, á sì jẹ́ kí ìgbàgbọ́ ẹ túbọ̀ lágbára.

Ìtàn Ìgbésí Ayé Nínú Àwọn Ìwé Ìròyìn Wa

Wàá rí ìlujá sí ọ̀pọ̀ ìtàn ìgbésí ayé àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà tó ti jáde nínú Ilé Ìṣọ́ àti Jí! látọdún 1955.

DORINA CAPARELLI

Bó Tiẹ̀ Jẹ́ Pé Mo Máa Ń Tijú, Iṣẹ́ Yìí Náà Ni Màá Tún Fáyé Mi Ṣe!

Dorina ṣiṣẹ́ aṣáájú-ọ̀nà déédéé, aṣáájú-ọ̀nà àkànṣe, alábòójútó arìnrìn-àjò, ó tún sìn ní Bẹ́tẹ́lì. Ó rántí ohun tó fẹ́rẹ̀ẹ́ tó àádọ́rin (70) ọdún tó ti lò lẹ́nu iṣẹ́ ìsìn alákòókò kíkún, àwọn ìbùkún tó gbádùn àti bí Jèhófà ṣe ràn án lọ́wọ́.

JESÚS MARTÍN

“Jèhófà Gbà Mí Sílẹ̀ Lákòókò tó Nira Jù Lọ Nígbèésí Ayé Mi”

Láwọn ọdún tí Jesús fí dá wà lọ́gbà ẹ̀wọ̀n tó ṣókùnkùn biribiri sí àwọn ọdún tó fi gbádùn àkànṣe iṣẹ́ ìsìn alákòókò kíkún, ó kẹ́kọ̀ọ́ nínú àwọn ìrírí tó ní pé, kéèyàn gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà ló dáa jù lọ.

GEORGIY PORCHULYAN

“Jèhófà Fìfẹ́ Hàn Sí Mi Jálẹ̀ Ìgbésí Ayé Mi”

Ó di Ẹlẹ́rìí Jèhófà níbi tó ti ń wá ìfọ̀kànbalẹ̀. Jèhófà fìfẹ́ hàn sí i ní gbogbo ìgbà tó fi wà ní àgọ́ ìṣẹ́niníṣẹ̀ẹ́ àti nígbèkùn, ìyẹn sì fún un lókun láti tọ́jú ìyàwó rẹ̀ ọ̀wọ́n.

DAYRELL SHARP

Jèhófà Ni Ò Jẹ́ Ká Fà Sẹ́yìn

Láìka àwọn ìṣòro tí wọ́n kojú sí, Dayrell àti Susanne Sharp ran àwọn tó lé ní àádóje lọ́wọ́ láti ṣèrìbọmi.

MILTIADIS STAVROU

“Jèhófà Bójú Tó Wa, Ó sì Tọ́ Wa Sọ́nà Jálẹ̀ Ìgbésí Ayé Wa”

Àwọn ìṣòro tí Milto àti Doris ìyàwó ẹ̀ ní lẹ́nu iṣẹ́ míṣọ́nnárì ní Middle East kọ́ wọn pé Jèhófà nìkan ló yẹ kí wọ́n gbára lé, kì í ṣe ara wọn.

Máà bínú, kò sóhun tó jọ ohun tó ò ń wá.