Àwọn Ohun Tí Wọ́n Lò Láti Kọ Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Sílẹ̀

Àwọn Ohun Tí Wọ́n Lò Láti Kọ Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Sílẹ̀

Àwọn ohun tí wọ́n lò láti kọ̀wé láyé àtijọ́ ti yàtọ̀ sáwọn tá à ń lóde òní, àmọ́ ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ò yí pa dà, ó ṣì wúlò títí dòní.