Àkójọ Àpilẹ̀kọ àti Fídíò

Onírúurú àpilẹ̀kọ títí kan èyí tó máa ń wà ní ìbẹ̀rẹ̀ jw.org ló wà ní abala yìí. Máa kà wọ́n kó o sì máa wo àwọn fídíò tó wà níbẹ̀, ìyẹn á jẹ́ kó túbọ̀ dá ẹ lójú pé àwọn ìmọ̀ràn Bíbélì máa ń ṣe wá láǹfààní.

Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!

Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Bí Ọ̀gbẹlẹ̀ Ṣe Túbọ̀ Ń Ṣẹlẹ̀ Kárí Ayé?

Ṣé a lè rí ojútùú ìṣòro yìí? Ṣé ìrètí wà pé nǹkan ṣì máa dáa?

Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!

Ṣé Ó Yẹ Kí Àwọn Kristẹni Lọ́wọ́ Sí Ogun​—Kí Ni Bíbélì Sọ?

Ṣé àwọn Kristẹni tó ń lọ́wọ́ sí ogun ń tẹ̀ lé àṣé Jésù?

Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!

Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Bí Ooru Ṣe Ń Mú Gan-an Kárí Ayé?

Ṣé ìgbà kan ń bọ̀ tí ayé yìí ò ní ṣeé gbé mọ́?

Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!

Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Bí Wọ́n Ṣe Ń Yìnbọn Pa Àwọn Èèyàn Nípakúpa Kárí Ayé?

Ṣé ìgbà kan ń bọ̀ tírú ìwà ipá yìí máa dópin?

Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!

Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Bí Àwọn Èèyàn Ṣe Ń Ba Ayé Yìí Jẹ́?

Ẹsẹ Bíbélì kan sọ ohun mẹ́ta nípa ìṣòro ojú ọjọ́ tó ń ba ayé jẹ́.

Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!

Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Bí Nǹkan Ṣe Túbọ̀ Ń Gbówó Lórí Kárí Ayé?

Kí nìdí tí ipò ọrọ̀ ajé fi túbọ̀ ń burú sí i? Báwo ni Bíbélì ṣe lè ràn wá lọ́wọ́?

Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!

Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Bí Wọ́n Ṣe Ń Yìnbọn Pa Àwọn Èèyàn Nílé Ìwé?

Kí nìdí táwọn ìṣẹ̀lẹ̀ burúkú yìí fi ń ṣẹlẹ̀? Ṣé ìwà ipá yìí tiẹ̀ lè dópin?

Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!

Ogun Tó Ń Jà Ní Ukraine Ti Dá Kún Ìṣòro Àìtó Oúnjẹ

Bíbélì sọ tẹ́lẹ̀ pé àìtó oúnjẹ máa wà, ó sì fún wa láwọn ìmọ̀ràn tó lè ràn wá lọ́wọ́ tá a bá bá ara wa nírú ipò yẹn. Ó tún fi wá lọ́kàn balẹ̀ pé ọ̀la máa dáa.

Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!

Àrùn Kòrónà Ti Pa Mílíọ̀nù Mẹ́fà Èèyàn​—Kí Ni Bíbélì Sọ?

Bíbélì sọ tẹ́lẹ̀ nípa àjàkálẹ̀ àrùn, ó tún sọ ohun tó lè tù wá nínú àti bí ìṣòro náà ṣe máa yanjú pátápátá.

Kí Ni Bíbélì Sọ Tẹ́lẹ̀ Nípa Àwọn Ìmìtìtì Ilẹ̀ Tó Lágbára?

Wo àpẹẹrẹ àwọn ìmìtìtì ilẹ̀ tó wáyé lẹ́nu àìpẹ́ yìí àti ohun tí Bíbélì sọ tó jẹ́ ká mọ ohun tó máa ṣẹlẹ̀ lọ́jọ́ iwájú.

Ṣé Ìwà Ìbàjẹ́ Tí Àwọn Ìjọba Ń Hù Máa Dópin?

Wàá rí ìdí mẹ́ta tó fi dá wa lójú pé kò ní sí ìwà ìbàjẹ́ lábẹ́ Ìjọba Ọlọ́run.

Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!

Kí Ni Bíbélì Sọ Nípa Lílo Ère Nínú Ìjọsìn?

Ṣé inú Ọlọ́run máa dùn tá a bá ń lò ère nínú ìjọsìn wa?

Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!

Ohun Táwọn Ẹlẹ́sìn Ń Ṣe Nípa Ogun Tó Ń Jà Nílẹ̀ Ukraine—Kí Ni Bíbélì Sọ?

Àwọn àlùfáà ṣọ́ọ̀ṣì lórílẹ̀-èdè méjèèjì ń rọ àwọn ọmọ ìjọ wọn pé kí wọ́n ṣe ohun tó yàtọ̀ sí ohun tí Jésù ní káwọn ọmọlẹ́yìn ẹ̀ máa ṣe.

Ẹ MÁA ṢỌ́NÀ!

Ogun Lé Ọ̀pọ̀ Èèyàn Kúrò Lórílẹ̀-Èdè Ukraine

Bíbélì sọ ohun tó fà á gan-an àti bí Ọlọ́run ṣe máa yanjú ìṣòro náà.

Orílẹ̀-èdè Rọ́ṣíà Gbógun Wọ Orílẹ̀-èdè Ukraine

Tó bá rí bẹ́ẹ̀, ṣé Bíbélì sọ ibi táwọn ohun tó ń ṣẹlẹ̀ yìí máa já sí?

Ṣé Bíbélì Lè Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́ Láti Jáwọ́ Nínú Lílo Oògùn Nílòkulò?

Àwọn ìgbésẹ̀ mẹ́rin tó dá lórí Bíbélì tó lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti borí ìṣòro oògùn tó di bárakú fún ẹ.

Ohun Tí Bíbélì Sọ Nípa Ojú Ọjọ́ Tó Ń Yí Pa Dà àti Ọjọ́ Ọ̀la Wa

Ṣé Ẹlẹ́dàá wa bìkítà nípa ayé àtàwọn tó ń gbébẹ̀?

Ṣé Nǹkan Ṣì Lè Pa Dà sí Bó Ṣe Wà Tẹ́lẹ̀ Ṣáájú Àrùn Corona? Bí Bíbélì Ṣe Lè Ràn Wá Lọ́wọ́

Àwọn ìlànà Bíbélì mẹ́fà tó lè ràn wá lọ́wọ́ láti kojú àwọn nǹkan tó ṣeé ṣe kó ṣẹlẹ̀.

Ṣé Ó Yẹ Káwọn Ẹlẹ́sìn Lọ́wọ́ sí Òṣèlú?

Kárí ayé, ọ̀pọ̀ àwọn tó pera wọn ní ọmọ ẹ̀yìn Jésù ló ń lọ́wọ́ sí òṣèlú. Ṣé ó yẹ kí wọ́n ṣe bẹ́ẹ̀?

Ṣé Ìgbà Kan Ń Bọ̀ Táwọn Olówó Àtàwọn Tálákà Máa Ní Nǹkan Lọ́gbọọgba?

Ìjọba kan wà tó lè pín nǹkan lọ́gbọọgba, kó sì mú ipò òṣì kúrò.

Ṣé Bíbélì Lè Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́ Láti Fara Da Àjálù Tí Ojú Ọjọ́ Máa Ń Fà?

Bíbélì lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti mọ ohun tó o máa ṣe kí àjálù tí ojú ọjọ́ máa ń fà tó ṣẹlẹ̀, tó bá ń ṣẹlẹ̀ lọ́wọ́ àti lẹ́yìn tó bá ṣẹlẹ̀.

Ìgbà Wo La Máa Bọ́ Lọ́wọ́ Àwọn Afẹ̀míṣòfò?

Títí dìgbà tá a máa bọ́ lọ́wọ́ àwọn oníwà ipá àtàwọn afẹ̀míṣòfò, Bíbélì sọ ohun méjì tá a lè ṣe láti fara dà á táwọn èèyànkéèyàn bá ṣọṣẹ́.

Ṣé Ayé Ò Ní Pẹ́ Pa Run? Kí Ni Àpókálíìsì?

Bó tilẹ̀ jẹ́ pé Bíbélì sọ pé ayé máa wà títí láé, ayé kan wà tó máa pa run.

Bó O Ṣe Lè Dáàbò Bo Ara Ẹ Lọ́wọ́ Àwọn Ìsọfúnni Tí Kì Í Ṣòótọ́

Ìròyìn tó ń ṣi ni lọ́nà, ìròyìn èké àti àhesọ ọ̀rọ̀ pọ̀ káàkiri, wọ́n sì lè ṣàkóbá fúnni.

Tí Ẹni Tó O Fẹ́ràn Bá Kú

Wo fídíò yìí kó o lè mọ ohun tó o lè ṣe kára lè tù ẹ́ tó o bá ń ṣọ̀fọ̀.

Ṣé A Ṣì Lè Gbára Lé Àwọn Ìlànà Bíbélì Lórí Ohun Tó Tọ́ àti Ohun Tí Kò Tọ́?

Wàá rí ìdí méjì tó fi yẹ ká gbára lé àwọn ìlànà Bíbélì.

Bó O Ṣe Lè Borí Àníyàn

Àwọn ìmọ̀ràn àtàwọn ẹsẹ Bíbélì wo ló lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti borí àníyàn?

Ìdí Tó Fi Dá Wa Lójú Pé Ọ̀la Máa Dáa

Kí nìdí táwọn ìlérí tó wà nínú Bíbélì fi yàtọ̀ sáwọn ìlérí táwọn èèyàn máa ń ṣe?

Ṣé Ẹ̀sìn Ti Wá Di Òwò Tó Ń Mówó Rẹpẹtẹ Wọlé?

Àwọn ṣọ́ọ̀ṣì kan wà tí ọ̀pọ̀ àwọn tó ń lọ síbẹ̀ jẹ́ aláìní, ṣùgbọ́n tí àwọn pásítọ̀ wọn ní ọrọ̀ rẹpẹtẹ.

Ohun Méje Tí Ò Ní Jẹ́ Kí Oúnjẹ Léwu Táá sì Ṣara Lóore

Ìwàláàyè jẹ́ ẹ̀bùn, a sì ń fi hàn pé a mọrírì rẹ̀ tá a bá ń bójú tó ìlera wa àti ti ìdílé wa. Ronú nípa ọ̀nà tó o lè gbà ṣe bẹ́ẹ̀.

Ta Ló Máa Tún Ayé Yìí Ṣe?

Àwọn kan tó jẹ́ onímọ̀ nípa àyíká sọ pé ohun táwọn èèyàn ń ṣe sí ayé lè mú kí onírúurú ẹ̀dá alààyè pòórá pátápátá lórí ilẹ̀ ayé ó sì ń ṣèpalára fún àyíká àtàwọn ẹranko ju ti ìgbàkígbà rílọ.

Ohun Tó O Lè Ṣe tí Àjàkálẹ̀ Àrùn Bá Ṣẹlẹ̀

Tí àjàkálẹ̀ àrùn bá ṣẹlẹ̀, kí lo lè ṣe tí kò fi ní kó bá ìlera ẹ àti àjọṣe ẹ pẹ̀lú Ọlọ́run, tí wàá sì máa láyọ̀?

Báwo Ni Bíbélì Ṣe Lè Ran Àwọn Ọkùnrin Tó Ń Ṣàníyàn Lọ́wọ́?

Àníyàn túbọ̀ ń pọ̀ sí i láwọn àkókò tí nǹkan le gan-an yìí. Ṣé Bíbélì lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ tó o bá ń kojú ìṣòro àníyàn?

Ohun Tó O Lè Ṣe Kí Àrùn Corona Má Bàa Jẹ́ Kí Nǹkan Tojú Sú Ẹ

Tá ò bá jà fitafita, ó lè bẹ̀rẹ̀ sí í sú wa láti dáàbò bo ara wa lọ́wọ́ àrùn Corona.

Ṣé Ìdájọ́ Òdodo Máa Wà?

Bíbélì jẹ́ ká mọ̀ pé ọ̀dọ̀ Ọlọ́run, tí ẹ̀mí gbogbo èèyàn jọ lójú, ni ìdájọ́ òdodo á ti wá.

Bíbélì Ìtumọ̀ Ayé Tuntun tá a tún ṣe ti wà lédè Spanish

Lédè Spanish ọ̀rọ̀ kan lè ní ìtumọ̀ oríṣiríṣi, báwo làwọn tó túmọ̀ Bíbélì náà ṣe ṣeé?

Ohun Tó O Lè Ṣe Tí Àìsàn Bá Dé Láìròtẹ́lẹ̀

Àwọn ìsọfúnni tó wúlò wo ló wà nínú Bíbélì tó lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ tí ìlera rẹ bá burú sí i láìròtẹ́lẹ̀?

Bó O Ṣe Lè Máa Ṣọ́wó Ná

Lóòótọ́, nǹkan kì í bára dé téèyàn bá pàdánù iṣẹ́ tó ń mówó wọlé fún un, àmọ́ àwọn ọ̀rọ̀ ọgbọ́n tó wà nínú Bíbélì lè ṣèrànwọ́ kéèyàn lè mọ́ bá a ṣe máa ṣọ́ ìwọ̀nba owó tó wà lọ́wọ́ ná.

Bó O Ṣe Lè Yẹra fún Ọtí Àmujù

Àbá márùn-un tó máa ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti mọ̀wọ̀n ara ẹ nídìí ọtí kódà tí nǹkan ò bá tiẹ̀ rọrùn fún ẹ.

Ìrànlọ́wọ́ fún Àwọn tí Wọ́n Ń Fìyà Jẹ Nínú Ilé

Mọ̀ pé ìwọ kọ́ lo lẹ̀bi, o ò sì dá wà.

Ohun Tó O Lè Ṣe Tó Ò Bá Lómìnira Àtijáde Bíi Ti Tẹ́lẹ̀

Tí ohùn kan bá ṣẹlẹ̀ tó ò sì lè kúrò nílé, má ṣe rò pé gbogbo nǹkan máa dàrú, pé o ò lè láyọ̀ àti pé ó lè má sí ọ̀nà àbáyọ.

Ṣé Jòhánù Arinibọmi Wà Lóòótọ́?

Òpìtàn ọgọ́rùn-ún ọdún kìíní náà Josephus gbà pé Jòhánù Arinibọmi tí gbé ayé rí, torí náà, ó yẹ káwa náà gbà bẹ́ẹ̀.

Àkọsílẹ̀ Ayé Àtijọ́ Kan Jẹ́rìí Sí Ibi Tí Ẹ̀yà Ísírẹ́lì Kan Ti Wà

Àwọn àpáàdì tí wọ́n hú jáde nílùú Samáríà jẹ́rìí sí i pé òótọ́ làwọn ìtàn tó wà nínú Bíbélì.

Èdìdì Ayé Àtijọ́​—Kí Ni Wọ́n?

Kí nìdìí táwọn èdìdì ayé àtijọ́ fi ṣe pàtàkì? Báwo làwọn ọba àtàwọn alákòóso ṣe ń lò wọ́n?

Ṣé Ohun Tí Bíbélì Sọ Nípa Àwọn Júù Nígbèkùn Bábílónì Jóòótọ́?

Ṣé àwọn ọ̀jọ̀gbọ́n gbà pé ohun tí Ọlọ́run sọ nípa ìgbésí ayé àwọn Júù nígbèkùn Bábílónì ṣẹlẹ̀ lóòótọ́?

Àwòrán Tí Wọ́n Gbẹ́ Sára Ògiri ní Íjíbítì Àtijọ́ Ti Ohun Tí Bíbélì Sọ Lẹ́yìn

Kà nípa bí àwòrán kan tó wà ní Íjíbítì àtijọ́ ṣe jẹ́ ká túbọ̀ rí i pé òótọ́ lohun tó wà nínú Bíbélì.

Àwọn Òfin Ọlọ́run Lórí Ìmọ́tótó Là Wọ́n Lójú Gan-an

Orílẹ̀-èdè Ísírẹ́lì àtijọ́ jàǹfààní gan-an bí wọ́n ṣe ń pa àwọn òfin gíga Ọlọ́run mọ́ lórí ọ̀rọ̀ ìmọ́tótó.

Àìtó Ẹ̀jẹ̀​—Ohun Tó Ń Fà Á, Bó Ṣe Máa Ń Ṣe Àwọn Tó Ní In àti Ìtọ́jú Rẹ̀

Kí là ń pè ní àìtó ẹ̀jẹ̀? Ṣé ó ṣeé dènà, ṣé ó sì ṣeé wò sàn?

Ìwádìí Àwọn Awalẹ̀pìtàn Jẹ́ Ká Rí I Pé Ọba Dáfídì Gbé Láyé Rí Lóòótọ́

Àwọn alárìíwísí kan sọ pé ìtàn àròsọ lásán ni ìtàn Ọba Dáfídì, pé àwọn èèyàn ló hùmọ̀ ẹ̀. Àmọ́, kí làwọn awalẹ̀pìtàn rí?

Ìwé Àfọwọ́kọ Àtijọ́ Kan Ṣètìlẹ́yìn fún Lílo Orúkọ Ọlọ́run

Wo ẹ̀rí tó fi hàn pé orúkọ Ọlọ́run wà nínú “Májẹ̀mú Tuntun.”

Ètò Kíka Bíbélì

Ìbáà jẹ́ ètò Bíbélì kíkà ojoojúmọ́ lò ń wá tàbí ti ọdọọdún tàbí èyí tó wà fẹ́ni tó ṣẹ̀ṣẹ̀ fẹ́ máa ka Bíbélì, ètò Bíbélì kíkà yìí máa wúlò fún ẹ.

Báwo Ni Ìwàláàyè Ṣe Bẹ̀rẹ̀?

Òótó ibẹ̀ ni pé ọ̀pọ̀ àwọn tó kàwé, títí kan àwọn onímọ̀ sáyẹ́ǹsì kan ni ò fara mọ́ ọn pé òótọ́ ni ẹ̀kọ́ ẹfolúṣọ̀n.

Bó O Ṣe Lè Wá Ẹsẹ Ìwé Mímọ́ Nínú Bíbélì Rẹ

Bó o ṣe lè wá ẹsẹ ìwé mímọ́ nínú Bíbélì rẹ: Bá a ṣe to àwọn ìwé mẹ́rìndínláàádọ́rin (66) tó wà nínú Bíbélì síbí ni wọ́n ṣe tò ó tẹ̀ léra nínú ọ̀pọ̀ ìtumọ̀ Bíbélì. Lẹ́yìn orúkọ ìwé, nọ́ńbà tó tẹ̀ lé e ni orí, nọ́ńbà tó wá tẹ̀ lé ìyẹn ni ẹsẹ.

Wọ́n Mọyì Bíbélì

William Tyndale àti Michael Servetus jẹ́ méjì lára àwọn tó fi èmí ara wọn wewu, tí wọn ò sì fi iyì ara wọn láwùjọ pè kí wọ́n lè kọ́ àwọn èèyàn lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì láìka àtakò àti ìhalẹ̀mọ́ni sí.

Wọ́n Mọyì Bíbélì​—Díẹ̀ Nínú Ìtàn William Tyndale

Àwọn iṣẹ́ tó ṣe fi hàn pé ó nífẹ̀ẹ́ Bíbélì, a sì ń jàǹfààní látinú ẹ̀ títí dòní.

ABALA ÌBẸ̀RẸ̀

ÀWỌN MÍÌ

Tí Ẹni Tó O Fẹ́ràn Bá Kú

Wo fídíò yìí kó o lè mọ ohun tó o lè ṣe kára lè tù ẹ́ tó o bá ń ṣọ̀fọ̀.

Ohun Méje Tí Ò Ní Jẹ́ Kí Oúnjẹ Léwu Táá sì Ṣara Lóore

Ìwàláàyè jẹ́ ẹ̀bùn, a sì ń fi hàn pé a mọrírì rẹ̀ tá a bá ń bójú tó ìlera wa àti ti ìdílé wa. Ronú nípa ọ̀nà tó o lè gbà ṣe bẹ́ẹ̀.

Ohun Tó O Lè Ṣe tí Àjàkálẹ̀ Àrùn Bá Ṣẹlẹ̀

Tí àjàkálẹ̀ àrùn bá ṣẹlẹ̀, kí lo lè ṣe tí kò fi ní kó bá ìlera ẹ àti àjọṣe ẹ pẹ̀lú Ọlọ́run, tí wàá sì máa láyọ̀?

Bíbélì Ìtumọ̀ Ayé Tuntun tá a tún ṣe ti wà lédè Spanish

Lédè Spanish ọ̀rọ̀ kan lè ní ìtumọ̀ oríṣiríṣi, báwo làwọn tó túmọ̀ Bíbélì náà ṣe ṣeé?

Ṣé Jòhánù Arinibọmi Wà Lóòótọ́?

Òpìtàn ọgọ́rùn-ún ọdún kìíní náà Josephus gbà pé Jòhánù Arinibọmi tí gbé ayé rí, torí náà, ó yẹ káwa náà gbà bẹ́ẹ̀.

Àkọsílẹ̀ Ayé Àtijọ́ Kan Jẹ́rìí Sí Ibi Tí Ẹ̀yà Ísírẹ́lì Kan Ti Wà

Àwọn àpáàdì tí wọ́n hú jáde nílùú Samáríà jẹ́rìí sí i pé òótọ́ làwọn ìtàn tó wà nínú Bíbélì.

Èdìdì Ayé Àtijọ́​—Kí Ni Wọ́n?

Kí nìdìí táwọn èdìdì ayé àtijọ́ fi ṣe pàtàkì? Báwo làwọn ọba àtàwọn alákòóso ṣe ń lò wọ́n?

Ṣé Ohun Tí Bíbélì Sọ Nípa Àwọn Júù Nígbèkùn Bábílónì Jóòótọ́?

Ṣé àwọn ọ̀jọ̀gbọ́n gbà pé ohun tí Ọlọ́run sọ nípa ìgbésí ayé àwọn Júù nígbèkùn Bábílónì ṣẹlẹ̀ lóòótọ́?

Àwòrán Tí Wọ́n Gbẹ́ Sára Ògiri ní Íjíbítì Àtijọ́ Ti Ohun Tí Bíbélì Sọ Lẹ́yìn

Kà nípa bí àwòrán kan tó wà ní Íjíbítì àtijọ́ ṣe jẹ́ ká túbọ̀ rí i pé òótọ́ lohun tó wà nínú Bíbélì.

Àwọn Òfin Ọlọ́run Lórí Ìmọ́tótó Là Wọ́n Lójú Gan-an

Orílẹ̀-èdè Ísírẹ́lì àtijọ́ jàǹfààní gan-an bí wọ́n ṣe ń pa àwọn òfin gíga Ọlọ́run mọ́ lórí ọ̀rọ̀ ìmọ́tótó.

Àìtó Ẹ̀jẹ̀​—Ohun Tó Ń Fà Á, Bó Ṣe Máa Ń Ṣe Àwọn Tó Ní In àti Ìtọ́jú Rẹ̀

Kí là ń pè ní àìtó ẹ̀jẹ̀? Ṣé ó ṣeé dènà, ṣé ó sì ṣeé wò sàn?

Ìwádìí Àwọn Awalẹ̀pìtàn Jẹ́ Ká Rí I Pé Ọba Dáfídì Gbé Láyé Rí Lóòótọ́

Àwọn alárìíwísí kan sọ pé ìtàn àròsọ lásán ni ìtàn Ọba Dáfídì, pé àwọn èèyàn ló hùmọ̀ ẹ̀. Àmọ́, kí làwọn awalẹ̀pìtàn rí?

Ìwé Àfọwọ́kọ Àtijọ́ Kan Ṣètìlẹ́yìn fún Lílo Orúkọ Ọlọ́run

Wo ẹ̀rí tó fi hàn pé orúkọ Ọlọ́run wà nínú “Májẹ̀mú Tuntun.”

Ètò Kíka Bíbélì

Ìbáà jẹ́ ètò Bíbélì kíkà ojoojúmọ́ lò ń wá tàbí ti ọdọọdún tàbí èyí tó wà fẹ́ni tó ṣẹ̀ṣẹ̀ fẹ́ máa ka Bíbélì, ètò Bíbélì kíkà yìí máa wúlò fún ẹ.

Báwo Ni Ìwàláàyè Ṣe Bẹ̀rẹ̀?

Òótó ibẹ̀ ni pé ọ̀pọ̀ àwọn tó kàwé, títí kan àwọn onímọ̀ sáyẹ́ǹsì kan ni ò fara mọ́ ọn pé òótọ́ ni ẹ̀kọ́ ẹfolúṣọ̀n.

Bó O Ṣe Lè Wá Ẹsẹ Ìwé Mímọ́ Nínú Bíbélì Rẹ

Bó o ṣe lè wá ẹsẹ ìwé mímọ́ nínú Bíbélì rẹ: Bá a ṣe to àwọn ìwé mẹ́rìndínláàádọ́rin (66) tó wà nínú Bíbélì síbí ni wọ́n ṣe tò ó tẹ̀ léra nínú ọ̀pọ̀ ìtumọ̀ Bíbélì. Lẹ́yìn orúkọ ìwé, nọ́ńbà tó tẹ̀ lé e ni orí, nọ́ńbà tó wá tẹ̀ lé ìyẹn ni ẹsẹ.

Wọ́n Mọyì Bíbélì​—Díẹ̀ Nínú Ìtàn William Tyndale

Àwọn iṣẹ́ tó ṣe fi hàn pé ó nífẹ̀ẹ́ Bíbélì, a sì ń jàǹfààní látinú ẹ̀ títí dòní.

Wọ́n Mọyì Bíbélì

William Tyndale àti Michael Servetus jẹ́ méjì lára àwọn tó fi èmí ara wọn wewu, tí wọn ò sì fi iyì ara wọn láwùjọ pè kí wọ́n lè kọ́ àwọn èèyàn lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì láìka àtakò àti ìhalẹ̀mọ́ni sí.

Máà bínú, kò sóhun tó jọ ohun tó ò ń wá.