“JẸ́RÌÍ KÚNNÁKÚNNÁ NÍPA ÌJỌBA ỌLỌ́RUN”

Wọ́n Ń Kọ́ni “ní Gbangba àti Láti Ilé dé Ilé”

Yorùbá
Wọ́n Ń Kọ́ni “ní Gbangba àti Láti Ilé dé Ilé”
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/1102009065/univ/art/1102009065_univ_sqr_xl.jpg
bt ojú ìwé 156

APÁ 7 • ÌṢE 18:23–21:17

Wọ́n Ń Kọ́ni “ní Gbangba àti Láti Ilé dé Ilé”

Wọ́n Ń Kọ́ni “ní Gbangba àti Láti Ilé dé Ilé”

ÌṢE 20:20

Kí nìdí tá a fi gbọ́dọ̀ jẹ́ onírẹ̀lẹ̀, ká sì máa mú ọ̀rọ̀ wa bá ipò onírúurú èèyàn tá à ń kọ́ lẹ́kọ̀ọ́ mu? Ọ̀nà pàtàkì wo la gbà ń wàásù ìhìn rere? Báwo la ṣe lè fi hàn pé ó ṣe pàtàkì ká máa ṣe ìfẹ́ Ọlọ́run ju ká tẹ́ ara wa lọ́rùn lọ? A máa rí ìdáhùn àwọn ìbéèrè pàtàkì yìí nínú àkọsílẹ̀ tó ń múnú ẹni dùn nípa ìrìn àjò míṣọ́nnárì ẹlẹ́ẹ̀kẹta tí Pọ́ọ̀lù rìn kẹ́yìn.