“JẸ́RÌÍ KÚNNÁKÚNNÁ NÍPA ÌJỌBA ỌLỌ́RUN”

“Ẹ Ti Fi Ẹ̀kọ́ Yín Kún Jerúsálẹ́mù”

Yorùbá
“Ẹ Ti Fi Ẹ̀kọ́ Yín Kún Jerúsálẹ́mù”
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/1102009042/univ/art/1102009042_univ_sqr_xl.jpg
bt ojú ìwé 13

APÁ 1 • ÌṢE 1:1–6:7

“Ẹ Ti Fi Ẹ̀kọ́ Yín Kún Jerúsálẹ́mù”

“Ẹ Ti Fi Ẹ̀kọ́ Yín Kún Jerúsálẹ́mù”

ÌṢE 5:28

Ní Pẹ́ńtíkọ́sì ọdún 33 Sànmánì Kristẹni, Ọlọ́run tú ẹ̀mí mímọ́ sórí àwọn ọmọ ẹ̀yìn Jésù. Àtìgbà yẹn làwọn ọmọ ẹ̀yìn náà ti túbọ̀ ń lo àkókò wọn láti máa jẹ́rìí nípa Ìjọba Ọlọ́run. Nínú apá yìí, a máa sọ̀rọ̀ nípa àwọn nǹkan amóríyá tó ṣẹlẹ̀ nígbà tí wọ́n dá ìjọ Kristẹni sílẹ̀, báwọn ọmọ ẹ̀yìn ṣe fìtara wàásù ní Jerúsálẹ́mù àti báwọn àpọ́sítélì ṣé ń fìgboyà báṣẹ́ lọ lójú àtakò tó le gan-an.