“JẸ́RÌÍ KÚNNÁKÚNNÁ NÍPA ÌJỌBA ỌLỌ́RUN”

“Àwọn Àpọ́sítélì àti Àwọn Alàgbà Kóra Jọ”

Yorùbá
“Àwọn Àpọ́sítélì àti Àwọn Alàgbà Kóra Jọ”
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/1102009064/univ/art/1102009064_univ_sqr_xl.jpg
bt ojú ìwé 100

APÁ 5 • ÌṢE 15:1-35

“Àwọn Àpọ́sítélì àti Àwọn Alàgbà Kóra Jọ”

“Àwọn Àpọ́sítélì àti Àwọn Alàgbà Kóra Jọ”

ÌṢE 15:6

Awuyewuye kan tó lágbára wáyé tó lè mú kó nira fáwọn ará láti wà níṣọ̀kan, kí àlàáfíà sì wà láàárín wọn. Ta ló máa fún wọn ní ìtọ́ni tó ṣeé gbára lé táá jẹ́ kí wọ́n lè yanjú awuyewuye náà? Ní apá yìí, a máa kẹ́kọ̀ọ́ nípa bí Ọlọ́run ṣe ṣètò ìjọ ní ọgọ́rùn-ún ọdún kìíní, àá sì rí bí ìyẹn ṣe jẹ́ àpẹẹrẹ rere fáwa èèyàn Ọlọ́run lónìí.