Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Gbogbo Àròpọ̀ ti Ọdún 2015

Gbogbo Àròpọ̀ ti Ọdún 2015
  • Iye Ẹ̀ka Ọ́fíìsì Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà: 89

  • Iye Orílẹ̀-Èdè Tó Ròyìn: 240

  • Àròpọ̀ Iye Ìjọ: 118,016

  • Àwọn Tó Wá Síbi Ìrántí Ikú Kristi Kárí Ayé: 19,862,783

  • Àwọn Tó Jẹ Ohun Ìṣàpẹẹrẹ Kárí Ayé: 15,177

  • Góńgó Akéde: 8,220,105

  • Ìpíndọ́gba Akéde Tó Ń Wàásù Lóṣooṣù: 7,987,279

  • Iye Tá A Fi Pọ̀ Ju Ti Ọdún 2014: 1.5

  • Àròpọ̀ Iye Àwọn Tó Ṣèrìbọmi: 260,273

  • Ìpíndọ́gba Aṣáájú-Ọ̀nà Olùrànlọ́wọ́ Lóṣooṣù: 443,504

  • Ìpíndọ́gba Aṣáájú-Ọ̀nà Déédéé Lóṣooṣù: 1,135,210

  • Àròpọ̀ Wákàtí Tá A Lò Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìwàásù: 1,933,473,727

  • Ìpíndọ́gba Àwọn Tá À Ń Kọ́ Lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Lóṣooṣù: 9,708,968

Ní ọdún iṣẹ́ ìsìn 2015, ó ju igba ó lé mẹ́rìndínlógójì [236] mílíọ̀nù owó dọ́là táwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ná láti bójú tó àwọn aṣáájú-ọ̀nà àkànṣe, àwọn míṣọ́nnárì àtàwọn alábòójútó arìnrìn-àjò lẹ́nu iṣẹ́ wọn. Bákan náà, kárí ayé, iye àwọn tó ń ṣiṣẹ́ láwọn ẹ̀ka ọ́fíìsì wa jẹ́ ẹgbẹ̀rún mẹ́rìndínlọ́gbọ̀n, ó lé mọ́kànlá [26,011]. Wọ́n wà lára Àwọn Tó Ń Ṣe Àkànṣe Iṣẹ́ Ìsìn Alákòókò Kíkún Lára Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà.