Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

APÁ KẸRIN

“Èmi Yóò Fi Ìtara Gbèjà Orúkọ Mímọ́ Mi”​—Ìjọsìn Mímọ́ Borí Àtakò

“Èmi Yóò Fi Ìtara Gbèjà Orúkọ Mímọ́ Mi”​—Ìjọsìn Mímọ́ Borí Àtakò

ÌSÍKÍẸ́LÌ 39:25

OHUN TÍ APÁ YÌÍ DÁ LÉ: Jèhófà máa dáàbò bo àwọn èèyàn rẹ̀ nígbà ìpọ́njú ńlá

Jèhófà nífẹ̀ẹ́ àwa èèyàn, síbẹ̀, ó máa ń fẹ́ ká jíhìn fún ohunkóhun tá a bá ṣe. Báwo ló ṣe máa ń rí lára rẹ̀ táwọn tó pe ara wọn ní olùjọ́sìn rẹ̀ bá ń ṣe ohun tó tàbùkù sí i? Báwo ló ṣe máa pinnu ẹni tó máa la ìpọ́njú ńlá já? Kí sì nìdí tí Jèhófà, Ọlọ́run tó nífẹ̀ẹ́ aráyé fi máa pa ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ẹni burúkú run?

NÍ APÁ YÌÍ

ORÍ 15

“Èmi Yóò Fòpin sí Iṣẹ́ Aṣẹ́wó Rẹ”

Kí la lè rí kọ́ látinú àpèjúwe àwọn aṣẹ́wó tí ìwé Ìsíkíẹ́lì àti Ìfihàn sọ̀rọ̀ nípa wọn?

ORÍ 16

“Sàmì sí Iwájú Orí” Wọn

Bí wọ́n ṣe sàmì sí àwọn olóòótọ́ nígbà ayé Ìsíkíẹ́lì ṣe pàtàkì sí wa.

ORÍ 17

“Èmi Yóò Bá Ọ Jà, Ìwọ Gọ́ọ̀gù”

Ta ni Gọ́ọ̀gù ti Ilẹ̀ Mágọ́gù, ilẹ̀ wo ló sì gbógun jà?

ORÍ 18

“Inú Á Bí Mi Gidigidi”

Jèhófà máa bínú gidigidi nígbà tí Gọ́ọ̀gù bá gbéjà ko àwọn èèyàn Ọlọ́run, àmọ́ Jèhófà máa gbèjà àwọn èèyàn rẹ̀.