ÌJỌSÌN MÍMỌ́ JÈHÓFÀ TI PA DÀ BỌ̀ SÍPÒ!

Àsọtẹ́lẹ̀ Nípa Mèsáyà​—Igi Kédárì Ńlá

Yorùbá
Àsọtẹ́lẹ̀ Nípa Mèsáyà​—Igi Kédárì Ńlá
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/1102017930/univ/art/1102017930_univ_sqr_xl.jpg
rr ojú ìwé 86

ÀPÓTÍ Ẹ̀KỌ́ 8A

Àsọtẹ́lẹ̀ Nípa Mèsáyà​—Igi Kédárì Ńlá

Àsọtẹ́lẹ̀ Nípa Mèsáyà​—Igi Kédárì Ńlá

ÌSÍKÍẸ́LÌ 17:3-24

  • 1. Nebukadinésárì mú Jèhóákínì lọ sí Bábílónì

  • 2. Nebukadinésárì fi Sedekáyà sórí ìtẹ́ ní Jerúsálẹ́mù

  • 3. Sedekáyà ṣọ̀tẹ̀ sí Jèhófà, ó wá ìrànlọ́wọ́ lọ sí Íjíbítì nígbà tó fẹ́ jagun

  • 4. Jèhófà gbin Ọmọ rẹ̀ sórí Òkè Síónì ní ọ̀run

  • 5. Lábẹ́ òjìji Ìjọba Jésù, àwọn èèyàn tí wọ́n jẹ́ onígbọràn máa gbé lábẹ́ ààbò