GBÁDÙN AYÉ RẸ TÍTÍ LÁÉ!​—ÌJÍRÒRÒ LÁTINÚ BÍBÉLÌ

Ohun Tá A Tọ́ka Sí Ní Apá 4

Yorùbá
Ohun Tá A Tọ́ka Sí Ní Apá 4
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/1102021342/univ/art/1102021342_univ_sqr_xl.jpg
lff

Ohun Tá A Tọ́ka Sí Ní Apá 4

Ohun Tá A Tọ́ka Sí Ní Apá 4

 48 Fọgbọ́n Yan Àwọn Ọ̀rẹ́ Rẹ

Pinnu Láti Kọ Ẹgbẹ́ Búburú Sílẹ̀ Lákọ̀tán (6:17)

Wá Àwọn Ọ̀rẹ́ Ní Ibi Tí O Ò Lérò (5:06)

Ta Ni Ọ̀rẹ́ Tòótọ́? (4:14)

ṢÈWÁDÌÍ

Máa Fọgbọ́n Lo Ìkànnì Àjọlò (4:12)

 49 Báwo Ni Ìdílé Rẹ Ṣe Lè Láyọ̀?​—Apá Kìíní

Bí Tọkọtaya Ṣe Lè Túbọ̀ Ṣe Ara Wọn Lọ́kan (5:44)

ṢÈWÁDÌÍ

Ìfẹ́ Tòótọ́ (4:26)

Jèhófà Ló Bá Wa Tún Ìdílé Wa Tò (5:14)

 50 Báwo Ni Ìdílé Rẹ Ṣe Lè Láyọ̀?​—Apá Kejì

Dáàbò Bo Àwọn Ọmọ Rẹ Lọ́wọ́ Ibi (2:58)

Dáàbò Bo Ọmọ Rẹ (1:52)

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Máa Sọ Tinú Mi Fáwọn Òbí Mi? (2:19)

Ìjọsìn Ìdílé​—Àwọn Ìṣòro àti Ayọ̀ Ibẹ̀ (8:04)

ṢÈWÁDÌÍ

Jèhófà Ló Bá Wa Tọ́ Àwọn Ọmọ Wa (5:58)

 51 Báwo La Ṣe Lè Jẹ́ Kí Ọ̀rọ̀ Tá À Ń Sọ Múnú Jèhófà Dùn?

Máa Sọ “Ọ̀rọ̀ Tó Ń Gbéni Ró” Fáwọn Míì (4:07)

Ìfẹ́ àti Ọ̀wọ̀ Ń Mú Kí Ìdílé Wà Níṣọ̀kan (3:08)

ṢÈWÁDÌÍ

Ẹ Sapá Láti Ní Ahọ́n Ọlọ́gbọ́n (8:04)

Báwo Ni Mo Ṣe Lè Yẹra fún Òfófó? (2:36)

 52 Ìdí Tó Fi Yẹ Ká Máa Múra Lọ́nà Tó Bójú Mu

“Ẹ Máa Ṣe Ohun Gbogbo fún Ògo Ọlọ́run” (10:18)

ṢÈWÁDÌÍ

“Ìmúra àti Ìwọṣọ Ni Kò Jẹ́ Kí N Tètè Rí Òtítọ́” (Jí!, March 8, 2004)

 53 Yan Eré Ìnàjú Táá Múnú Jèhófà Dùn

Eré Ìnàjú Wo Ló Yẹ Kí N Yàn Láàyò? (4:39)

Báwo Lo Ṣe Ń Lo Àkókò Rẹ? (2:45)

ṢÈWÁDÌÍ

 54 Ta Ni “Ẹrú Olóòótọ́ àti Olóye?

Jèhófà Mú Kí Àwọn Èèyàn Rẹ̀ Wà Létòlétò (6:18)

Iṣẹ́ Ìwàásù La Kà Sí Pàtàkì Jù (1:24)

ṢÈWÁDÌÍ

Àǹfààní Ńlá Ni Kéèyàn Sìnrú fún Jèhófà (7:04)

Jèhófà Ń Kọ́ Àwa Èèyàn Rẹ̀ (9:39)

 55 Máa Ṣètìlẹyìn fún Ìjọ

‘Wọ́n Mú Ẹ̀bùn Wá fún Jèhófà’ (4:47)

Bá A Ṣe Lè Máa Bójú Tó Àwọn Ibi Ìjọsìn Wa (3:31)

ṢÈWÁDÌÍ

 56 Máa Ṣe Ohun Táá Jẹ́ Kí Àlàáfíà àti Ìṣọ̀kan Wà Nínú Ìjọ

Máa Wá Àlàáfíà Kó O Lè Rí Ìbùkún (6:01)

Máa Sunwọ̀n Sí I Lójoojúmọ́! (5:10)

ṢÈWÁDÌÍ

Yọ Igi ìrólé (6:56)

Má Ṣe Máa Fi Ìrísí Dáni Lẹ́jọ́ (5:06)

 57 Kí Lo Lè Ṣe Tó O Bá Dá Ẹ̀ṣẹ̀ Tó Burú Gan-an?

“Àwọn Tí Jèhófà Nífẹ̀ẹ́ Ló Máa Ń Bá Wí” (3:01)

ṢÈWÁDÌÍ

Aláàánú Ni Jèhófà (5:02)

 58 Jẹ́ Adúróṣinṣin sí Jèhófà

Ẹ Jáde Kúrò Nínú Bábílónì Ńlá! (5:06)

ṢÈWÁDÌÍ

Ẹ Má Ṣe Jẹ́ Kí Wọ́n Tàn Yín Jẹ (9:32)

 59 Jẹ́ Adúróṣinṣin sí Jèhófà Táwọn Èèyàn Bá Tiẹ̀ Ń Ta Kò Ẹ́

Jèhófà Ò Fi Wá Sílẹ̀ (5:13)

Jèhófà Máa Fún Mi Lókun (3:40)

ṢÈWÁDÌÍ

Jèhófà Ràn Án Lọ́wọ́ Láti Fara Da Inúnibíni (2:34)

Bá A Ṣe Sin Jèhófà Láwọn Àkókò Tí Nǹkan Ò Dẹrùn (7:11)

 60 Máa Ṣe Ohun Táá Jẹ́ Kó O Túbọ̀ Sún Mọ́ Jèhófà

Ìgbésí Ayé Tó Dára Jù Lọ (3:31)

ṢÈWÁDÌÍ

Ẹ Ní Ìgbàgbọ́ Bíi Ti Ábúráhámù (9:20)

“Fi Àwọn Ohun Tó Ò Ń Lé Nípa Tẹ̀mí Yin Ẹlẹ́dàá Rẹ Lógo” (Ilé Ìṣọ́, July 15, 2004)