ÀWỌN ẸSẸ BÍBÉLÌ TÓ LÈ RAN ÀWA KRISTẸNI LỌ́WỌ́

Ojúkòkòrò

Yorùbá
Ojúkòkòrò
/assets/ct/b4d7e1101e/images/syn_placeholder_sqr.png
scl Ojúkòkòrò

Ojúkòkòrò

Ojúkòkòrò

Lk 12:15; Kol 3:5

  • Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:

    • Nọ 11:4, 5, 31-33—Ojúkòkòrò mú káwọn ọmọ Ísírẹ́lì kó ẹyẹ àparò tó ju èyí tí wọ́n lè jẹ, Jèhófà sì fìyà jẹ wọ́n torí ohun tí wọ́n ṣe yẹn

    • 2Ọb 5:20-27—Ojúkòkòrò mú kí Géhásì parọ́ mọ́ wòlíì Èlíṣà, ó sì jìyà ohun tó ṣe