ÀWỌN ẸSẸ BÍBÉLÌ TÓ LÈ RAN ÀWA KRISTẸNI LỌ́WỌ́

Ìkọjá Àyè

Yorùbá
Ìkọjá Àyè
/assets/ct/2fee4a8a5e/images/syn_placeholder_sqr.png
scl Ìkọjá Àyè

Ìkọjá Àyè

Ìkọjá Àyè

Owe 11:2; 13:10

Tún wo Owe 21:24

  • Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:

    • 2Sa 6:6, 7—Úsà kọjá àyè ẹ̀ bó ṣe gbá Àpótí Ọlọ́run mú nígbà tó jọ pé àpótí náà fẹ́ ṣubú, Jèhófà sì pa á, torí ohun tó ṣe yẹn fi hàn pé kò bọ̀wọ̀ fún Jèhófà rárá

    • 2Kr 26:16-21—Jèhófà fìyà jẹ Ọba Ùsáyà torí pé ó hùwà tó fi hàn pé ó jẹ́ agbéraga