ÀWỌN ẸSẸ BÍBÉLÌ TÓ LÈ RAN ÀWA KRISTẸNI LỌ́WỌ́

Àwọn Àna

Yorùbá
Àwọn Àna
/assets/ct/2fee4a8a5e/images/syn_placeholder_sqr.png
scl Àwọn Àna

Àwọn Àna

Àwọn Àna

Tí ọkùnrin àti obìnrin kan bá ṣègbéyàwó, kí nìdí tí kò fi yẹ káwọn òbí àtàwọn àna máa tojú bọ ohun tó ń lọ nínú ìdílé wọn?

Jẹ 2:24; Mt 19:4, 5

Tún wo Sm 34:14; Mt 5:9; Ro 12:18; 14:10-13

  • Àpẹẹrẹ inú Bíbélì:

    • Ẹk 18:1-27—Mósè àti Jẹ́tírò tó jẹ́ bàbá ìyàwó ẹ̀ bọ̀wọ̀ fún ara wọn