Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Wá Ìdáhùn sí Àwọn Ìbéèrè Yìí

Wá Ìdáhùn sí Àwọn Ìbéèrè Yìí
  1. Kí nìdí tó fi dá wa lójú pé tá a bá gbàdúrà pé kí Jèhófà ràn wá lọ́wọ́ láti jẹ́ aláìṣojo, ó máa dá wa lóhùn? (Sm. 138:3)

  2. Báwo la ṣe lè jẹ́ aláìṣojo bí àwọn ìránṣẹ́ Ọlọ́run láyé àtijọ́? (Ìṣe 4:31)

  3. Báwo la ṣe lè mọ́kàn le lẹ́nu iṣẹ́ ìwàásù? (1 Tẹs. 2:2)

  4. Kí ló máa ràn wá lọ́wọ́ láti jẹ́ aláìṣojo táwọn èèyàn bá ń fúngun mọ́ wa? (1 Pét. 2:​21-23)

  5. Ìbùkún wo làwa Kristẹni máa rí tá a bá ní ìgboyà tá ò sì ṣojo? (Héb. 10:35)