Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Wá Ìdáhùn sí Àwọn Ìbéèrè Yìí

Wá Ìdáhùn sí Àwọn Ìbéèrè Yìí
  1. Ọ̀dọ̀ ta ni a ti lè rí okun àti agbára gbà? (Jóṣ. 1:9; Sm. 68:35)

  2. Báwo la ṣe lè túbọ̀ mú kí ìgbàgbọ́ wa lágbára? (Héb. 11:6)

  3. Kí nìdí tó fi dá wa lójú pé a máa ṣàṣeyọrí lẹ́nu iṣẹ́ tí Jèhófà fún wa? (Hág. 2:4-9)

  4. Báwo ni Jèhófà ṣe ń fún wa lókun nígbà tá a bá dojú kọ àdánwò tó lágbára? (Sm. 18:6, 30; Kól. 4:10, 11)

  5. Kí ló máa ran àwọn ọ̀dọ́ àtàwọn tọkọtaya lọ́wọ́ kí wọ́n lè fara mọ́ ìṣàkóso Jèhófà? (Mát. 22:37, 39)

  6. Báwo la ṣe lè “dúró gbọn-in gbọn-in nínú ìgbàgbọ́,” ká sì “di alágbára ńlá”? (1 Kọ́r. 16:13; Róòmù 15:5; Héb. 5:11–6:1; 12:16, 17)