Oju Iwe Ti Wọn Kọ Akọle Si/Oju Iwe Ti Wọn Kọ Orukọ Onṣewe Si
“Ete Aiyeraiye” Ọlọrun Nṣẹgun Nisisiyi FUN IRE ENIA
Ayẹwo Rampẹ kan Ti O Nlaniloye Nipa Ete Pataki Ẹlẹda Enia, lati Igba Ti A Ti Dá A Silẹ Ni Ẹgbata Ọdun Sẹhin Si Aṣepari Iyinlogo Ọlọrun pẹlu Awọn Ibukun Ti O Pọ Yanturu fun Gbogbo Araiye
A ya iwe yi si mimọ fun Ọlọrun ẹniti o ti wá gba enia là nipa ṣiṣeto “ete aiyeraiye” rẹ̀ niti Messiah rẹ̀

