Yorùbá
Oju Iwe Ti Wọn Kọ Akọle Si/Oju Iwe Ti Wọn Kọ Orukọ Onṣewe Si
/assets/ct/79e1b14fff/images/syn_placeholder_sqr.png
hp ojú ìwé 1-2
Oju Iwe Ti Wọn Kọ Akọle Si/Oju Iwe Ti Wọn Kọ Orukọ Onṣewe Si

Oju Iwe Ti Wọn Kọ Akọle Si/Oju Iwe Ti Wọn Kọ Orukọ Onṣewe Si

Ayọ—Bi A Ṣe Lè Rí I

Ọpọlọpọ eniyan ni wọn kuna lati ri ayọ̀. Ṣugbọn eyi le ṣalai rí bẹẹ ninu ọran tirẹ. Iriri awọn eniyan yika ayé fi ẹri hàn pe itẹlọrun ati igbesi-aye kan ti ó ni ẹ̀rí ninu wà larọwọto rẹ. A tẹ iwe yii lati lé mú ki isọfunni oniyebiye naa tí iwọ nilo lati le rí ayọ wà larọwọto rẹ.

​—Awa Tí A Tẹ Ẹ Sode