Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ 2019

Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ‘Ìfẹ́ Kì Í Yẹ̀ Láé’! ti Ọdún 2019.

Friday

Ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tá a gbé ìtòlẹ́sẹẹsẹ ọjọ́ Friday kà ni 1 Tẹsalóníkà 4:9​—“Ọlọ́run ti kọ́ yín láti máa nífẹ̀ẹ́ ara yín.”

Saturday

Ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tá a gbé ìtòlẹ́sẹẹsẹ ọjọ́ Saturday kà ni Éfésù 5:2—‘Ẹ máa rìn nínú ìfẹ́.’

Sunday

Ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tá a gbé ìtòlẹ́sẹẹsẹ ọjọ́ Sunday kà ni Júùdù 21—‘Ẹ dúró nínú ìfẹ́ Ọlọ́run.’

Ohun Tá A Fẹ́ Kí Àwọn Tó Wá Sí Àpéjọ Yìí Mọ̀

Ìsọfúnni tó wúlò fún àwọn tá a pè wá sí àpéjọ yìí.