ÌRÒYÌN IṢẸ́ ÌSÌN ÀWA ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ TI ỌDÚN 2024

Gbogbo Àròpọ̀ ti Ọdún 2024

Yorùbá
Gbogbo Àròpọ̀ ti Ọdún 2024
/assets/ct/29206d32a6/images/syn_placeholder_sqr.png
syr24 ojú ìwé 2

Gbogbo Àròpọ̀ ti Ọdún 2024

Gbogbo Àròpọ̀ ti Ọdún 2024
  • Iye Ẹ̀ka Ọ́fíìsì Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà: 84

  • Iye Orílẹ̀-Èdè Tó Ròyìn: 240

  • Iye Ìjọ: 118,767

  • Àwọn Tó Wá Síbi Ìrántí Ikú Kristi Kárí Ayé: 21,119,442

  • Àwọn Tó Jẹ Ohun Ìṣàpẹẹrẹ Kárí Ayé: 23,212

  • Iye Akéde a: 9,043,460

  • Ìpíndọ́gba Akéde Tó Ń Wàásù Lóṣooṣù: 8,828,124

  • Iye Tá A Fi Pọ̀ Ju Ti Ọdún 2023: 203,082

  • Iye Àwọn Tó Ṣèrìbọmi b: 296,267

  • Ìpíndọ́gba Aṣáájú-Ọ̀nà Déédéé c Lóṣooṣù: 1,679,026

  • Ìpíndọ́gba Aṣáájú-Ọ̀nà Olùrànlọ́wọ́ Lóṣooṣù: 867,502

  • Ìpíndọ́gba Àwọn Tá À Ń Kọ́ Lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì d Lóṣooṣù: 7,480,146

Ọdún iṣẹ́ ìsìn 2024 bẹ̀rẹ̀ láti September 1, 2023 sí August 31, 2024.

a Akéde ni ẹni tó ń kéde tàbí tó ń wàásù ìhìn rere Ìjọba Ọlọ́run déédéé. (Mátíù 24:14) Tó o bá fẹ́ àlàyé nípa bá a ṣe mọ iye àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà, wo àpilẹ̀kọ náà “Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Mélòó Ló Wà Kárí Ayé?” lórí jw.org.

b Tó o bá fẹ́ mọ̀ sí i nípa àwọn nǹkan tẹ́nì kan máa ṣe kó tó lè ṣèrìbọmi láti di ọ̀kan lára àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà, wo àpilẹ̀kọ náà “Báwo Ni Mo Ṣe Lè Di Ẹlẹ́rìí Jèhófà?” lórí jw.org.

c Aṣáájú-ọ̀nà ni Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan tó ti ṣèrìbọmi, tó níwà tó dáa, tó sì pinnu láti máa lo iye wákàtí kan pàtó lẹ́nu iṣẹ́ ìwàásù ìhìn rere lóṣooṣù.

d Tó o bá fẹ́ mọ̀ sí i, wo àpilẹ̀kọ tá a pè ní “Kí Ni Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Táwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Máa Ń Kọ́ Àwọn Èèyàn?” lórí jw.org.