Ìmọ̀ Tí Ń Sinni Lọ sí Ìyè Àìnípẹ̀kun

Ọ̀rọ̀ Iṣáájú

Yorùbá
Ọ̀rọ̀ Iṣáájú
/assets/ct/fa815d8e9f/images/syn_placeholder_sqr.png
kl ojú ìwé 4-5
Ọ̀rọ̀ Iṣáájú

Ọ̀rọ̀ Iṣáájú

Àwọn àyíká ẹlẹ́wà bí ìwọ̀nyí lè jẹ́ tìrẹ títí láé!

Kí ni o gbọ́dọ̀ ṣe láti gbádùn wọn? Ìdáhùn náà wà nínú irú àkànṣe ìmọ̀ kan.

Ìwé yìí yóò ràn ọ́ lọ́wọ́ láti jèrè ìmọ̀ náà tí ń sinni lọ sí ìyè àìnípẹ̀kun.