Yorùbá
Ohun Tí Mo Rò—Bí Nǹkan Ṣe Ń Rí Lára Ẹ
/assets/ct/28ada02fb0/images/syn_placeholder_sqr.png
yp2 ojú ìwé 243
Ohun Tí Mo Rò—Bí Nǹkan Ṣe Ń Rí Lára Ẹ

APÁ 7

Ohun Tí Mo Rò—Bí Nǹkan Ṣe Ń Rí Lára Ẹ

Èrò wo ló máa ń da ọkàn ẹ láàmú jù lọ, báwo ló sì ṣe máa ń rí lára ẹ?

․․․․․

Kí lo ti rí nínú ìsọfúnni tó wà nínú apá keje ìwé yìí tó máa ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti wá nǹkan ṣe sírú èrò bẹ́ẹ̀, bó bá tún wá sí ẹ lọ́kàn?

․․․․․