Yorùbá
Ohun Tí Mo Rò—Ọ̀rọ̀ Ọkùnrin àti Obìnrin
/assets/ct/a5f5be13b3/images/syn_placeholder_sqr.png
yp2 ojú ìwé 55
Ohun Tí Mo Rò—Ọ̀rọ̀ Ọkùnrin àti Obìnrin

APÁ 1

Ohun Tí Mo Rò—Ọ̀rọ̀ Ọkùnrin àti Obìnrin

Bó bá wù ẹ́ láti ṣègbéyàwó, kọ àwọn ànímọ́ méjì tó ṣe pàtàkì jù lọ tó máa wù ẹ́ kí ẹni tó o máa fẹ́ ní, kó o sì ṣàlàyé ìdí táwọn ànímọ́ wọ̀nyẹn fi wù ẹ́. Bó bá sì wù ẹ́ pé kó o dúró díẹ̀ kó o tó ṣègbéyàwó, kọ àwọn àǹfààní bíi méjì tó wà nínú kéèyàn wà láìṣègbéyàwó.

․․․․․