Yorùbá
Ohun Tí Mo Rò—Àjọṣe Rẹ Nínú Ìdílé
/assets/ct/fa815d8e9f/images/syn_placeholder_sqr.png
yp1 ojú ìwé 55
Ohun Tí Mo Rò—Àjọṣe Rẹ Nínú Ìdílé

APÁ 1

Ohun Tí Mo Rò​—Àjọṣe Rẹ Nínú Ìdílé

Sọ ìṣòro kan tó wáyé láìpẹ́ yìí láàárín ìwọ àti ọ̀kan lára àwọn tẹ́ ẹ jọ wà nínú ìdílé.

․․․․․

Báwo lo ṣe lè lo àwọn àbá tó o ti kà nínú apá kìíní yìí láti fi yanjú ìṣòro náà? Kọ ìdáhùn rẹ sí ibí yìí.

․․․․․