Ara Èèpo Iwájú Ìwé

Àlàyé

Yorùbá
Àlàyé
/assets/ct/28ada02fb0/images/syn_placeholder_sqr.png
yp1 ojú ìwé 3
Àlàyé

Àlàyé

Lára Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí Ni. . .

ÀWỌN ẸSẸ ÌWÉ MÍMỌ́

tó ṣàlàyé àwọn kókó pàtàkì

ÌMỌ̀RÀN

àwọn àbá tó máa jẹ́ kó o lè ṣàṣeyọrí

ṢÓ O MỌ̀ PÉ . . .

àwọn kókó pàtàkì tó máa mú kó o ronú jinlẹ̀

OHUN TÍ MÀÁ ṢE!

ibi tó o ti máa lè kọ bó o ṣe máa lo ohun tó o bá kà nínú ìwé yìí

KÍ LÈRÒ Ẹ?

àwọn ìbéèrè tó máa mú kó o ronú lórí ohun tó o kà

Ní Àfikún . . .

OHUN TÍ MO RÒ

ojú ewé kan wà ní ìparí apá kọ̀ọ̀kan nínú ìwé yìí, tí wàá lè kọ ohun tó o rò sí

ÀWÒKỌ́ṢE

a sọ̀rọ̀ nípa àwọn èèyàn kan nínú Bíbélì tó jẹ́ pé o lè tẹ̀ lé àpẹẹrẹ wọn