ILÉ ÌṢỌ́ September 2014 | Ṣé Àwọn Èèyàn Ò Ní Ba Ayé Yìí Jẹ́ Kọjá Àtúnṣe?

Kí la lè ṣe táyé yìí ò fi ní bà jẹ́ kọjá àtúnṣe?

KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ

Ǹjẹ́ Àwọn Èèyàn Ò Ní Ba Ayé Yìí Jẹ́ Kọjá Àtúnṣe?

Bíbélì sọ tẹ́lẹ̀ nípa bí àwọn èèyàn ṣe ń ba àyíká jẹ́, ó tún sọ nípa ohun tó máa ṣẹlẹ̀ lẹ́yìnwá ọ̀la.

Ǹjẹ́ Òfin Tí Ọlọ́run Fún Àwọn Ọmọ Ísírẹ́lì Bá Ẹ̀tọ́ Mu?

Àwọn ìlànà mẹ́rin tí ó tọ́ àwọn onídàájọ́ Ísírẹ́lì sọ́nà.

ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ

Ìgbésí Ayé Mi Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìsìn Ọlọ́run Mérè Wá

Ohun kan ṣẹlẹ̀ sí Peter Carrbello ní ọdún márùndínláàádọ́rin sẹ́yìn tó mú kó ṣe àwọn àyípadà kan nínú ìgbésí ayé rẹ̀.

Bíbélì Peshitta Lédè Síríákì—Bíbélì kan Tó Jẹ́ Ká Mọ Bí Wọ́n Ṣe Túmọ̀ Bíbélì Láyé Àtijọ́

Bíbélì àtijọ́ yìí fi hàn pé àwọn Bíbélì kan lóde òní ní àwọn àfikún tí kò sí nínú Bíbélì ìpilẹ̀ṣẹ̀.

Ohun Tí Bíbélì Sọ

Ṣó tọ́ ká máa gbàdúrà sáwọn áńgẹ́lì fún ìrànlọ́wọ́?

Àwọn Nǹkan Míì Tó Wà Lórí Ìkànnì

Kí Ni Ìjọba Ọlọ́run?

Ṣàgbéyẹ̀wò ìdí tí ìjọba Ọlọ́run fi dára ju gbogbo ìjọba yòókù lọ.