ILÉ ÌṢỌ́ September 2013 | Kí Nìdí Tí Ìyà Fi Pọ̀ Láyé? Ìgbà Wo Ló Máa Dópin?
Kí ni Bíbélì sọ nípa ìyà tó ń jẹ àwa èèyàn, báwo ló sì ṣe máa nípa lórí aráyé tó?
KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ
Àìmọye Aláìṣẹ̀ Ló Ti Ṣègbé!
Aráyé ń jìyà láìsí ìdí kan tó ṣe gúnmọ́. Ṣẹ́ ẹ̀bi Ọlọ́run ni?
KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ
Kí nìdí tí ìyà fi pọ̀ tó báyìí?
Mọ àwọn ohun márùn ún tó fa ìyà lónìí, àti ibi tí a ti lè rí ojúlówó ìrètí.
KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ
Ìyà Máa Dópin Láìpẹ́!
Ọlọ́run ti ṣèlérí pé òun má mú gbogbo ohun tó ń fa ìyà kúrò. Báwo ló ṣe máa ṣe é, ìgbà wo sì ni?
ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ
Tálákà Ni Wá àmọ́ À Ń Fi Ayọ̀ Sin Ọlọ́run
Alexander Ursu rí i pé kò sẹ́ni tó lè dá ìjọsìn Ọlọ́run dúró, kódà ìjọba Soviet Union àtijọ́ kò lè dá a dúró. Ka ìtàn alárinrin kan nípa ìtàn ìgbésí ayé ẹnì yìí.
Ṣé Ilé Gogoro Bábélì Ni Èdè Wa Ti Bẹ̀rẹ̀?
Kí ni ilé Gogoro Bábélì? Níbo ni èdè àwa èèyàn ti ṣẹ̀ wá?
SÚN MỌ́ ỌLỌ́RUN
“Ọlọ́run Nífẹ̀ẹ́ Olùfúnni Ọlọ́yàyà”
Wádìí nípa ohun tó yẹ ká ní lọ́kàn tá a bá ń fúnni ní nǹkan.
KỌ ỌMỌ RẸ
Ohun Tí O Bá Ṣe Lè Dùn Ọlọ́run—Bí O Ṣe Lè Mú Inú Rẹ̀ Dùn
Ǹjẹ́ o mọ̀ pé ohun tí o bá ṣe lè mú kí inú Ọlọ́run dùn tàbí kó bà á nínú jẹ́? Mọ̀ nípa ohun tí Ádámù àti Éfà ṣe tí ó dun Jèhófà.
Ohun Tí Bíbélì Sọ
Àwọn ìmọ̀ràn Bíbélì nípa bí tọkọtaya ṣe lè láyọ̀ wúlò gan-an, torí pé Jèhófà Ọlọ́run tó ṣètò ìgbéyàwó ló fún wa ni àwọn ìmọ̀ràn náà.
Àwọn Nǹkan Míì Tó Wà Lórí Ìkànnì
Ibo Làwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ti Ń Rówó Tí Wọ́n Ń Ná?
A ò kì í gba owó báwọn oníṣọ́ọ̀ṣì ṣe ń gba owó.

