Yorùbá
Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì
/assets/ct/2fee4a8a5e/images/syn_placeholder_sqr.png
w09 7/1 ojú ìwé 32
Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì

Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì

◼ Tó o bá fẹ́ lóye Bíbélì, ibo lo ti lè rí ìrànlọ́wọ́? Wo ojú ìwé 6 sí 8.

◼ Ṣé èèyàn lè ní àlàáfíà ọkàn nínú ayé oníwàhálà yìí? Wo ojú ìwé 10 sí 12.

◼ Ṣé wọ́n ti rí ọkọ̀ Nóà? Wo ojú ìwé 13 àti 14.

◼ Ta ni Ábígẹ́lì, kí la sì lè rí kọ́ lóde òní látara ìgbàgbọ́ tó ní? Wo ojú ìwé 18 sí 21.

◼ Ṣé Ọlọ́run fọwọ́ sí ìkóbìnrinjọ? Wo ojú ìwé 30.