ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ March 2025

Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti May 5–June 8, 2025 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 9

Má Jẹ́ Kí Ohunkóhun Dí Ẹ Lọ́wọ́ Láti Ṣèrìbọmi

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní May 5-11, 2025.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 10

Máa Ronú Bí Jèhófà àti Jésù Ṣe Ń Ronú

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní May 12-18, 2025.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 11

Máa Fìtara Wàásù Bíi Jésù

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní May 19-25, 2025.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 12

Máa Ṣe Ohun Tó Fi Hàn Pé O Nígbàgbọ́

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní May 26–June 1, 2025.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 13

Ọwọ́ Jèhófà Ò Kúrú

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní June 2-8, 2025.

OHUN TÓ O LÈ FI KẸ́KỌ̀Ọ́

Máa Fi Bíbélì Yẹ Ara Ẹ Wò Bíi Dígí

Báwo lo ṣe lè fi Bíbélì yẹ ara ẹ wò bíi dígí?