Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Atọ́ka Àwọn Àkòrí fún Ilé Ìṣọ́ 2015

Atọ́ka Àwọn Àkòrí fún Ilé Ìṣọ́ 2015

Ó ń tọ́ka sí Ilé Ìṣọ́ tí àpilẹ̀kọ kọ̀ọ̀kan ti jáde

ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

 • A Lè Jẹ́ Oníwà Mímọ́, 6/15

 • Àwọn Ọ̀nà Wo Ni Jèhófà Ń Gbà Fìfẹ́ Hàn sí Wa? 9/15

 • Bá A Ṣe Lè Fi Kún Ẹwà Párádísè Tẹ̀mí, 7/15

 • Báwo La Ṣe Lè Fi Hàn Pé A Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà? 9/15

 • Bí Àwọn Alàgbà Ṣe Ń Kọ́ Àwọn Míì Kí Wọ́n Lè Tóótun, 4/15

 • ÀWỌN ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ

 • “Àkókò Tá A Mọyì Jù Lọ” (Ìrántí Ikú Kristi), 2/15

 • ‘Ẹ Máa Ka Irú Àwọn Ènìyàn Bẹ́ẹ̀ Sí Ẹni Ọ̀wọ́n’ (àwọn tó ń ṣèrànwọ́ fún Ìgbìmọ̀ Olùdarí), 10/15

 • Ìdí Tí Ìyọlẹ́gbẹ́ Fi Jẹ́ Ìpèsè Onífẹ̀ẹ́, 4/15

 • Ìfẹ́ Mú Kí Nǹkan Wà Létòletò Nílé Ìjẹun, 5/15

 • “Jèhófà Mú Yín Wá sí Ilẹ̀ Faransé Láti Kẹ́kọ̀ọ́ Òtítọ́” (àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Poland tó wá sí ilẹ̀ Faransé lẹ́yìn Ogun Àgbáyé Kìíní), 8/15

 • Ọ̀KAN-Ò-JỌ̀KAN

 • Àníyàn, 7/1

 • Aṣòdì sí Kristi, 6/1

 • Àwọn Kìnnìún Kú Tán ní Agbègbè Ísírẹ́lì, 5/1

 • Balógun Ọgọ́rùn-ún Nínú Ẹgbẹ́ Ọmọ Ogun Róòmù, 4/1

 • Báwo Lo Ṣe Lè Jẹ́ Òbí Rere? 6/1

 • Báwo Ni Ìwà Ìmọtara-Ẹni-Nìkan Ṣe Máa Dópin? 4/1

 • Bí Wọ́n Ṣe Ń Sanwó Iṣẹ́ fún Àwọn Olùṣọ́ Àgùntàn, 3/1

 • Bó O Ṣe Lè Dàgbà Lọ́nà Tó Ń Yẹni, 6/1

 • Bó O Ṣe Lè Tọ́ Àwọn Ọmọ Rẹ Yanjú, 6/1

 • Dígí Láyé Ìgbà Tí Wọ́n Ń Kọ Bíbélì, 4/1

 • “Èmi Ha Wà ní Ipò Ọlọ́run Bí?” (Jósẹ́fù), 5/1

 • Ẹ̀bùn Tó Tọ́ Sí Ọba (èròjà atasánsán), 3/1

 • Ẹlẹ́dàá Wà, 1/1

 • Gbogbo Ayé Lábẹ́ Ìjọba Kan Ṣoṣo, 2/1

 •