ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́

Ṣé Wàá Fẹ́ Ká Bẹ̀ Ọ́ Wò?

Yorùbá
Ṣé Wàá Fẹ́ Ká Bẹ̀ Ọ́ Wò?
/assets/ct/79e1b14fff/images/syn_placeholder_sqr.png
w00 6/1 ojú ìwé 32
Ṣé Wàá Fẹ́ Ká Bẹ̀ Ọ́ Wò?

Ṣé Wàá Fẹ́ Ká Bẹ̀ Ọ́ Wò?

Àní nínú ayé onídààmú yìí, ìmọ̀ pípéye láti inú Bíbélì nípa Ọ

lọ́run, Ìjọba rẹ̀, àti ète àgbàyanu rẹ̀ fún aráyé, lè fún ọ láyọ̀. Bí o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i tàbí kí ẹnì kan kàn sí ọ nílé láti darí ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì pẹ̀lú rẹ lọ́fẹ̀ẹ́, jọ̀wọ́ kọ̀wé sí Watch Tower, P.M.B. 1090, Benin City, Edo State, Nigeria, tàbí sí àdírẹ́sì tí ó bá yẹ lára èyí tí a tò sí ojú ìwé 2.