Atọ́ka Àwọn Àkòrí fún Jí! ! 2016
“Ẹ ṣeun tí ẹ̀ ń tẹ àwọn ìwé ìròyìn tó bágbà mu yìí jáde.”
Ìyá ọlọ́mọ ni Amy, ìwé ìròyìn Jí! sì ti ràn án lọ́wọ́ kó lè máa ṣe ojúṣe rẹ̀ lójoojúmọ́. Bíi ti Amy, ọ̀pọ̀lọpọ̀ èèyàn ti jàǹfààní nínú kíka ìwé ìròyìn tó ń jáde lẹ́ẹ̀kan lóṣù méjì yìí. Lọ sí ìkànnì wa www.jw.org/yo, kó o lè ṣàyẹ̀wò àwọn àpilẹ̀kọ tá a tẹ̀ jáde lọ́dún 2016, bá a ṣe tò wọ́n síbi yìí.
ÀJỌṢE ÀWỌN ÈÈYÀN
ÌFỌ̀RỌ̀WÁNILẸ́NUWÒ
Onímọ̀ Nípa Ọlẹ̀ Ṣàlàyé Ohun Tó Gbà Gbọ́ (Y. Hsuuw): No. 2
ILẸ̀ ÀTI ÀWỌN ÈÈYÀN
Kyrgyzstan: No. 4
Ẹ̀SÌN
SÁYẸ́ǸSÌ

