JÍ! No. 3 2020 | Ṣé Ìkórìíra Lè Dópin?
Ọ̀pọ̀ lára wa ló máa ń sọ pé àwọn kan máa ń ṣe ẹ̀tanú tàbí pé wọ́n lẹ́mìí ìkórìíra. Ṣùgbọ́n, a lè má mọ̀ pé àwa náà máa ń ṣe ẹ̀tanú sáwọn kan.
Jẹ́ ká wo àwọn ìmọ̀ràn tó wúlò táá jẹ́ ká túbọ̀ máa fìfẹ́ hàn sí gbogbo èèyàn.
Ṣé O Ní Ìkórìíra?
Àwọn ìwà àti ìṣe wo ló lè fi hàn pé a ní ẹ̀tanú tàbí ìkórìíra?
Ṣé Òótọ́ Ni?
Tá a bá ń tẹ́tí sí ọ̀rọ̀ tí kì í ṣòótọ́ nípa àwọn mí ì, a lè bẹ̀rẹ̀ sí í fojú burúkú wò wọ́n. Wo ohun tí ọkùnrin kan tó ti ṣiṣẹ́ ológun rí sọ nípa ọ̀rọ̀ yìí.
Máa Gba Tàwọn Èèyàn Rò
Tó bá ṣẹlẹ̀ pé ẹnì kan kì í gba táwọn mí ì rò, àmì kí nìyẹn jẹ́?
Máa Wo Ìwà Rere Táwọn Èèyàn Ní
Ìgbéraga lè mú kéèyàn máa kórìíra àwọn ẹlòmíì. Báwo lá ṣe lè yẹra fún ìgbéraga?
Yan Onírúurú Èèyàn Lọ́rẹ̀ẹ́
Wo àǹfààní tó o máa rí tó o bá ń bá àwọn mí ì sọ̀rẹ́ yàtọ̀ sáwọn tó o gbà pé ẹ ti mọwọ́ ara yín.
Máa Fìfẹ́ Hàn Sáwọn Èèyàn
Tá a bá ń fìfẹ́ hàn sáwọn èèyàn, ẹ̀tanú àti ẹ̀mí ìkórìíra máa kúrò lọ́kàn wa. Wo àwọn nǹkan tó máa ràn wá lọ́wọ́.
Ìkórìíra Máa Dópin!
Ohun mẹ́rin wo ni Ìjọba Ọlọ́run máa ṣe láti mú ẹ̀tanú àti ìkórìíra kúrò?
Wọ́n Borí Ìkórìíra
Wo fídíò mẹ́ta tó jẹ́ ká rí báwọn kan ṣe borí ẹ̀tanú àti ìkórìíra.

