JÍ! No. 3 2019 | Ṣé Bíbélì Lè Mú Káyé Ẹ Dáa Sí I?
Ọjọ́ pẹ́ tí Bíbélì ti ń mú kí ayé àwọn èèyàn dára sí i. Ìwọ náà lè jàǹfààní tó o bá ń fi àwọn ìmọ̀ràn inú rẹ̀ sílò lójoojúmọ́.
Ìwé Àtijọ́ Kan Tó Wúlò Lóde Òní
Wo díẹ̀ lára àǹfààní táwọn kan rí torí pé wọ́n ń ka Bíbélì, wọ́n sì ń tẹ̀ lé àwọn ìmọ̀ràn inú rẹ̀.
Ìlera Tó Dáa
Àwọn ìlànà Bíbélì ń kọ́ wa bá a ṣe lè máa tọ́jú ara wa.
Sùúrù
A máa jàǹfààní tó pọ̀ tá a bá ń ṣe sùúrù tá a sì ń kápá ìmọ̀lára wa.
Ìdílé Aláyọ̀ àti Ọ̀rẹ́ Àtàtà
Tó o bá fẹ́ ní àjọṣe tó dáa pẹ̀lú àwọn mí ì, ńṣe ni kó o máa ṣoore fáwọn èèyàn dípò kó máa retí pé kí wọ́n máa ṣoore fúnẹ.
Gbígbọ́ Bùkátà
Báwo ni Bíbélì ṣe lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti dín ìṣòro owó kù?
Sún Mọ́ Ọlọ́run
Àwọn ìlànà Ọlọ́run tó wà nínú Bíbélì lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti sún mọ́ Ọlọ́run kó o sì ní èrò tó tọ́ nípa ìgbésí ayé. Wo bó o ṣe lè ṣe é.
Ìwé Tó Dáa Jù Lọ Láyé
Ìwádìí fi hàn pé Bíbélì ni ìwé tí wọ́n túmọ̀ sí èdè tó pọ̀ jù lọ, tó sì wà lọ́wọ́ àwọn èèyàn tó pọ̀ jù lọ.
Ohun tó wà nínú ìwé yìí: Ṣé Bíbélì Lè Mú Káyé Ẹ Dáa Sí I?
Àwọn ìmọ̀ràn tó wúlò wà nínú Bíbélì tó o lè fi darí ìgbésí ayé rẹ̀.

