Yorùbá
Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí: Àkóbá Wo Ni Ẹ̀rọ Ìgbàlódé Lè Ṣe Fún . . .
https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/102021050/univ/art/102021050_univ_sqr_xl.jpg
g21 No. 2 ojú ìwé 16

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

Ẹ̀rọ ìgbàlódé lè máa dọ́gbọ́n pani lára, téèyàn ò sì ní tètè mọ̀.

ÀKÓBÁ WO NI Ẹ̀RỌ ÌGBÀLÓDÉ LÈ ṢE FÚN . . .

  • Ìwọ Àtàwọn Ọ̀rẹ́ Ẹ?

  • Àwọn Ọmọ Ẹ?

  • Ọkọ àti Aya?

  • Ìrònú Ẹ?